• Heberu 12

    Ìtọ́ni ti Oluwa 1 NITORINA bi a ti fi awọsanmọ ti o kún to bayi fun awọn ẹlẹri yí wa ká, ẹ jẹ ki a pa ohun idiwọ gbogbo tì si apakan, ati ẹ̀ṣẹ ti o rọrun lati dì mọ wa, ki a si mã fi sũru sure ije ti a gbé ka iwaju wa,…

  • Heberu 13

    Ìsìn Tí Ó Wu Ọlọrun 1 KI ifẹ ará ki o wà titi. 2 Ẹ máṣe gbagbé lati mã ṣe alejò; nitoripe nipa bẹ̃ li awọn ẹlomiran ṣe awọn angẹli li alejò laimọ̀. 3 Ẹ mã ranti awọn onde bi ẹniti a dè pẹlu wọn, ati awọn ti a npọn loju bi ẹnyin tikaranyin pẹlu…

  • Filemoni 1

    1 PAULU, onde Kristi Jesu, ati Timotiu arakunrin wa, si Filemoni olufẹ ati alabaṣiṣẹ wa ọwọn, 2 Ati si Affia arabinrin wa, ati si Arkippu ọmọ-ogun ẹgbẹ wa, ati si ìjọ inu ile rẹ: 3 Ore-ọfẹ, ati alafia sí nyin, lati ọdọ Ọlọrun Baba wa, ati Jesu Kristi Oluwa. Ìfẹ́ ati Igbagbọ Tí Filemoni Ní…

  • Titu 1

    Ìkíni 1 PAULU, iranṣẹ Ọlọrun, ati Aposteli Jesu Kristi, gẹgẹ bi igbagbọ́ awọn ayanfẹ Ọlọrun, ati imọ otitọ ti mbẹ gẹgẹ bi ìwa-bi-Ọlọrun, 2 Ni ireti ìye ainipẹkun, ti Ọlọrun, Ẹniti kò le ṣèké, ti ṣe ileri ṣaju ipilẹṣẹ aiye; 3 Ṣugbọn ni akokò tirẹ̀ o fi ọ̀rọ rẹ̀ hàn ninu iwasu, ti a fi…

  • Titu 2

    Ẹ̀kọ́ tí ó Yè Kooro 1 ṢUGBỌN iwọ mã sọ ohun ti o yẹ si ẹkọ́ ti o yè kõro: 2 Ki awọn àgba ọkunrin jẹ ẹni iwọntunwọnsin, ẹni-ọ̀wọ, alairekọja, ẹniti o yè kõro ni igbagbọ́, ni ifẹ, ni sũru. 3 Bẹ̃ gẹgẹ ni ki awọn agba obinrin jẹ ẹni-ọ̀wọ ni iwa, ki nwọn má…

  • Titu 3

    Ìlànà nípa Ìwà Tí Ó Dára 1 MÃ rán wọn leti lati mã tẹriba fun awọn ijoye, ati fun awọn alaṣẹ, lati mã gbọ́ ti wọn, ati lati mã mura si iṣẹ rere gbogbo, 2 Ki nwọn má sọrọ ẹnikẹni ni ibi, ki nwọn má jẹ onija, bikoṣe ẹni pẹlẹ, ki nwọn mã fi ìwa…

  • 2rd Timoteu 1

    1 PAULU, Aposteli Kristi Jesu nipa ifẹ Ọlọrun, gẹgẹ bi ileri ìye ti mbẹ ninu Kristi Jesu, 2 Si Timotiu, ọmọ mi olufẹ ọwọn: Ore-ọfẹ, ãnu, ati alafia, lati ọdọ Ọlọrun Baba wá, ati Kristi Jesu Oluwa wa. Ìdúpẹ́ ati Ọ̀rọ̀ Ìwúrí 3 Mo dupẹ lọwọ Ọlọrun, ti emi nsìn lati ọdọ awọn baba mi…

  • 2rd Timoteu 2

    Ọmọ-Ogun Rere Ti Kristi Jesu 1 NITORINA, iwọ ọmọ mi, jẹ alagbara ninu ore-ọfẹ ti mbẹ ninu Kristi Jesu. 2 Ati ohun wọnni ti iwọ ti gbọ́ lọdọ mi lati ọwọ ọ̀pọlọpọ ẹlẹri, awọn na ni ki iwọ fi le awọn olõtọ enia lọwọ, awọn ti yio le mã kọ́ awọn ẹlomiran pẹlu. 3 Ṣe…

  • 2rd Timoteu 3

    Ìwà tí Àwọn Eniyan Yóo Máa Hù ní Ọjọ́ Ìkẹyìn 1 ṢUGBỌN eyi ni ki o mọ̀, pe ni ikẹhin ọjọ ìgbà ewu yio de. 2 Nitori awọn enia yio jẹ olufẹ ti ara wọn, olufẹ owo, afunnú, agberaga, asọ̀rọbuburu, aṣaigbọran si obi, alailọpẹ, alaimọ́, 3 Alainifẹ, alaile darijini, abanijẹ́, alaile-kó-ra-wọnnijanu, onroro, alainifẹ-ohun-rere, 4 Onikupani,…

  • 2rd Timoteu 4

    1 NITORINA mo paṣẹ fun ọ niwaju Ọlọrun, ati Kristi Jesu, ẹniti yio ṣe idajọ alãye ati okú, ati nitori ifarahàn rẹ̀ ati ijọba rẹ̀, 2 Wasu ọ̀rọ na; ṣe aisimi li akokò ti o wọ̀, ati akokò ti kò wọ̀; baniwi, ṣe itọ́ni, gbà-ni-niyanju pẹlu ipamọra ati ẹ̀kọ́ gbogbo. 3 Nitoripe ìgba yio de,…

  • 1th Timoteu 1

    1 PAULU, Aposteli Kristi Jesu, gẹgẹ bi aṣẹ Ọlọrun Olugbala wa, ati Kristi Jesu ireti wa; 2 Si Timotiu, ọmọ mi tõtọ ninu igbagbọ́: Ore-ọfẹ, ãnu, alafia lati ọdọ Ọlọrun Baba wá, ati Kristi Jesu Oluwa wa. Ìkìlọ̀ nípa Ẹ̀kọ́ Èké 3 Bi mo ti gba ọ niyanju lati joko ni Efesu, nigbati mo nlọ…

  • 1th Timoteu 2

    Ẹ̀kọ́ nípa Adura 1 NITORINA mo gbà nyin niyanju ṣaju ohun gbogbo, pe ki a mã bẹ̀bẹ, ki a mã gbadura, ki a mã ṣìpẹ, ati ki a mã dupẹ nitori gbogbo enia; 2 Fun awọn ọba, ati gbogbo awọn ti o wà ni ipo giga; ki a le mã lo aiye wa ni idakẹjẹ…

  • 1th Timoteu 3

    Irú Ẹni Tí Olùdarí Ìjọ Ní láti Jẹ́ 1 OTITỌ ni ọ̀rọ na, bi ẹnikan ba fẹ oyè biṣopu, iṣẹ rere li o nfẹ. 2 Njẹ biṣopu jẹ alailẹgan, ọkọ aya kan, oluṣọra, alairekọja, oniwa yiyẹ, olufẹ alejò ṣiṣe, ẹniti o le ṣe olukọ. 3 Ki o má jẹ ọmuti, tabi onijà, tabi olojukokoro, bikoṣe…

  • 1th Timoteu 4

    Àsọtẹ́lẹ̀ nípa Àkókò Ìyapa ninu Ẹ̀sìn 1 ṢUGBỌN Ẹmí ntẹnumọ ọ pe, ni igba ikẹhin awọn miran yio kuro ninu igbagbọ́, nwọn o mã fiyesi awọn ẹmí ti ntan-ni-jẹ, ati ẹkọ́ awọn ẹmí èṣu; 2 Nipa agabagebe awọn ti nṣeke, awọn ti ọkàn awọn tikarawọn dabi eyiti a fi irin gbigbona jó. 3 Awọn ti…

  • 1th Timoteu 5

    Iṣẹ́ sí Àwọn tí ó Gbàgbọ́ 1 MÁṢE ba alàgba wi, ṣugbọn ki o mã gba a niyanju bi baba; awọn ọdọmọkunrin bi arakunrin; 2 Awọn àgba obinrin bi iya; awọn ọdọmọbirin bi arabinrin ninu ìwa mimọ́. 3 Bọ̀wọ fun awọn opó ti iṣe opó nitõtọ. 4 Ṣugbọn bi opó kan ba li ọmọ tabi…

  • 1th Timoteu 6

    1 KI gbogbo awọn ti iṣe ẹrú labẹ ìrú mã ka awọn oluwa ti o ni wọn yẹ si ọla gbogbo, ki a má bã sọrọ-odi si orukọ Ọlọrun ati ẹkọ́ rẹ̀. 2 Awọn ti o si ni oluwa onigbagbọ́, ki nwọn máṣe gàn wọn nitori arakunrin ni nwọn; ṣugbọn ki nwọn tubọ mã sìn…

  • 2rd Tessalonika 1

    Ìkíni 1 PAULU, ati Silfanu, ati Timotiu, si ijọ Tessalonika, ninu Ọlọrun Baba wa ati Jesu Kristi Oluwa: 2 Ore-ọfẹ si nyin, ati alafia, lati ọdọ Ọlọrun Baba, ati Jesu Kristi Oluwa. Ìdájọ́ Nígbà Tí Jesu Bá Dé 3 Iṣẹ wa ni lati mã dupẹ lọwọ Ọlọrun nigbagbogbo nitori nyin, ará, ani gẹgẹ bi o…

  • 2rd Tessalonika 2

    Ẹni Ibi Nnì 1 ṢUGBỌN awa mbẹ̀ nyin, ará, nitori ti wíwa Jesu Kristi Oluwa wa, ati ti ipejọ wa sọdọ rẹ̀, 2 Ki ọkàn nyin ki o máṣe tete mì, tabi ki ẹ máṣe jaiya, yala nipa ẹmí, tabi nipa ọ̀rọ, tabi nipa iwe bi lati ọdọ wa wá, bi ẹnipe ọjọ Oluwa de.…

  • 2rd Tessalonika 3

    Ẹ Gbadura Fún Wa 1 LAKOTAN, ará, ẹ mã gbadura fun wa, ki ọ̀rọ Oluwa le mã sáre, ki o si jẹ ãyìn logo, ani gẹgẹ bi o ti ri lọdọ nyin: 2 Ati ki a le gbà wa lọwọ awọn aṣodi ati awọn enia buburu: nitoripe ki iṣe gbogbo enia li o gbagbọ́. 3…

  • 1st Tessalonika 1

    Ìkíni 1 PAULU, ati Silfanu, ati Timotiu, si ijọ awọn ara Tessalonika, ninu Ọlọrun Baba, ati ninu Jesu Kristi Oluwa: Ore-ọfẹ si nyin, ati alafia, lati ọdọ Ọlọrun Baba wa, ati Jesu Kristi Oluwa. Ìdúpẹ́ 2 Awa ndupẹ lọwọ Ọlọrun nigbagbogbo fun gbogbo nyin, awa nṣe iranti nyin ninu adura wa; 3 Li aisimi li…

  • 1th Tessalonika 2

    Iṣẹ́ Paulu ní Tẹsalonika 1 NITORI ẹnyin tikaranyin mọ̀, ará, irú iwọle wa si nyin pe kì iṣe lasan: 2 Ṣugbọn lẹhin ti awa ti jìya ṣaju, ti a si ti lo wa ni ilo itiju ni Filippi gẹgẹ bi ẹnyin ti mọ̀, awa ni igboiya ninu Ọlọrun wa lati sọ̀rọ ihinrere Ọlọrun fun nyin…

  • 1th Tessalonika 3

    1 NITORINA nigbati ara wa kò gba a mọ́, awa rò pe o dara ki a fi awa nikan sẹhin ni Ateni; 2 Awa si rán Timotiu, arakunrin wa, ati iranṣẹ Ọlọrun ninu ihinrere Kristi, lati fi ẹsẹ nyin mulẹ, ati lati tù nyin ninu niti igbagbọ́ nyin: 3 Ki a máṣe mu ẹnikẹni yẹsẹ…

  • 1th Tessalonika 4

    Ìgbé-Ayé Tí Ó Wu Ọlọrun 1 NJẸ li akotan, ará, awa mbẹ̀ nyin, awa si ngbà nyin niyanju ninu Jesu Oluwa, pe bi ẹnyin ti gbà lọwọ wa bi ẹnyin iba ti mã rìn, ti ẹnyin iba si mã wù Ọlọrun, ani gẹgẹ bi ẹnyin ti nrìn, ki ẹnyin le mã pọ̀ siwaju si i.…

  • 1th Tessalonika 5

    Ẹ Múra Sílẹ̀ De Ìpadàbọ̀ Oluwa 1 ṢUGBỌN niti akokò ati ìgba wọnni, ará, ẹnyin kò tun fẹ ki a kọ ohunkohun si nyin, 2 Nitoripe ẹnyin tikaranyin mọ̀ dajudaju pe, ọjọ Oluwa mbọ̀wá gẹgẹ bi olè li oru. 3 Nigbati nwọn ba nwipe, alafia ati ailewu; nigbana ni iparun ojijì yio de sori wọn…

  • Kolosse 1

    Ìkíni 1 PAULU, Aposteli Jesu Kristi nipa ifẹ Ọlọrun, ati Timotiu arakunrin wa, 2 Si awọn enia mimọ́ ati awọn ará wa olõtọ ninu Kristi ti o wà ni Kolosse: Ore-ọfẹ fun nyin, ati alafia, lati ọdọ Ọlọrun Baba wa, ati Jesu Kristi Oluwa. Adura Ọpẹ́ 3 Awa ndupẹ lọwọ Ọlọrun ati Baba Jesu Kristi…

  • Kolosse 2

    1 NITORI emi nfẹ ki ẹnyin ki o mọ̀ bi iwaya-ìja ti mo ni fun nyin ti pọ̀ to, ati fun awọn ará Laodikea, ati fun iye awọn ti kò ti iri oju mi nipa ti ara; 2 Ki a le tu ọkàn wọn ninu, bi a ti so wọn pọ̀ ninu ifẹ ati si…

  • Kolosse 3

    1 NJẸ bi a ba ti ji nyin dide pẹlu Kristi, ẹ mã ṣafẹri awọn nkan ti mbẹ loke, nibiti Kristi gbé wà ti o joko li ọwọ́ ọtun Ọlọrun. 2 Ẹ mã ronu awọn nkan ti mbẹ loke kì iṣe awọn nkan ti mbẹ li aiye. 3 Nitori ẹnyin ti kú, a si fi…

  • Kolosse 4

    1 ẸNYIN oluwa, ẹ ma fi eyiti o tọ́ ti o si dọgba fun awọn ọmọ-ọdọ nyin; ki ẹ si mọ̀ pe ẹnyin pẹlu ni Oluwa kan li ọrun. Ọ̀rọ̀ Ìyànjú 2 Ẹ mã duro ṣinṣin ninu adura igbà, ki ẹ si mã ṣọra ninu rẹ̀ pẹlu idupẹ; 3 Ju gbogbo rẹ̀, ẹ mã gbadura…

  • Filippi 1

    Ìkíni 1 PAULU ati Timotiu, awọn iranṣẹ Jesu Kristi, si gbogbo awọn enia mimọ́ ninu Kristi Jesu ti o wà ni Filippi, pẹlu awọn biṣopu ati awọn diakoni: 2 Ore-ọfẹ si nyin, ati alafia, lati ọdọ Ọlọrun Baba wa, ati Oluwa Jesu Kristi. Adura fún Àwọn Ará Filipi 3 Mo dupẹ lọwọ Ọlọrun mi fun…

  • Filippi 2

    Jesu Rẹ Ara Rẹ̀ Sílẹ̀ 1 NITORINA bi itunu kan ba wà ninu Kristi, bi iṣipẹ ifẹ kan ba si wà, bi ìdapọ ti Ẹmí kan ba wà, bi ìyọ́nu-anu ati iṣeun ba wà, 2 Ẹ mu ayọ̀ mi kún, ki ẹnyin ki o le jẹ oninu kanna, ki imọ̀ nyin ki o ṣọkan, ki…

  • Filippi 3

    Òdodo Tòótọ́ 1 LI akotan, ará, ẹ mã yọ̀ ninu Oluwa. Kì iṣe inira fun mi lati kọwe ohun kanna si nyin, ṣugbọn fun nyin o jẹ ailewu. 2 Ẹ kiyesara lọdọ awọn ajá, ẹ kiyesara lọdọ awọn oniṣẹ-buburu, ẹ kiyesara lọdọ awọn onilà. 3 Nitori awa ni onilà, ti nsìn Ọlọrun nipa ti Ẹmí,…

  • Filippi 4

    Ọ̀rọ̀ Ìyànjú 1 NITORINA, ẹnyin ará mi olufẹ, ti mo si nṣafẹri gidigidi, ayọ̀ ati ade mi, ẹ duro ṣinṣin bẹ̃ ninu Oluwa, ẹnyin olufẹ mi. 2 Emi mbẹ̀ Euodia, mo si mbẹ̀ Sintike, ki nwọn ni inu kanna ninu Oluwa. 3 Mo si bẹ ọ pẹlu, bi alajọru-ajaga mi tõtọ, ran awọn obinrin wọnni…

  • Efesu 1

    Ìkínni 1 PAULU, Aposteli Jesu Kristi nipa ifẹ Ọlọrun, si awọn enia mimọ́ ti o wà ni Efesu, ati si awọn onigbagbọ ninu Kristi Jesu: 2 Ore-ọfẹ si nyin, ati alafia, lati ọdọ Ọlọrun Baba wa ati Jesu Kristi Oluwa. Ibukun ti Ẹ̀mí Nípa Kristi 3 Olubukún li Ọlọrun ati Baba Jesu Kristi Oluwa wa,…

  • Efesu 2

    Láti Inú Ikú sí Inú Ìyè 1 ẸNYIN li a si ti sọ di àye, nigbati ẹnyin ti kú nitori irekọja ati ẹ̀ṣẹ nyin, 2 Ninu eyiti ẹnyin ti nrin rí gẹgẹ bi ipa ti aiye yi, gẹgẹ bi alaṣẹ agbara oju ọrun, ẹmí ti nṣiṣẹ nisisiyi ninu awọn ọmọ alaigbọran: 3 Ninu awọn ẹniti…

  • Efesu 3

    Iṣẹ́ Paulu láàrin Àwọn Tí Kì í Ṣe Juu 1 NITORI eyina, emi Paulu, ondè Jesu Kristi nitori ẹnyin Keferi, 2 Bi ẹnyin ba ti gbọ ti iṣẹ iriju ore-ọfẹ Ọlọrun, ti a fifun mi fun nyin: 3 Bi o ti ṣepe nipa ifihan li o ti fi ohun ijinlẹ nì hàn fun mi, (gẹgẹ…

  • Efesu 4

    Ìṣọ̀kan Ara Kristi 1 NITORINA emi ondè ninu Oluwa, mbẹ̀ nyin pe, ki ẹnyin ki o mã rìn bi o ti yẹ fun ìpe na ti a fi pè nyin, 2 Pẹlu irẹlẹ gbogbo ati inu tutù, pẹlu ipamọra, ẹ mã fi ifẹ farada a fun ẹnikeji nyin; 3 Ki ẹ si mã lakaka lati…

  • Efesu 5

    Gbígbé Ninu Ìmọ́lẹ̀ 1 NITORINA ẹ mã ṣe afarawe Ọlọrun bi awọn ọmọ ọ̀wọ́n; 2 Ẹ si mã rìn ni ifẹ, gẹgẹ bi Kristi pẹlu ti fẹ wa, ti o si fi ara rẹ̀ fun wa li ọrẹ ati ẹbọ fun Ọlọrun fun õrùn didun. 3 Ṣugbọn àgbere, ati gbogbo ìwa ẽrí, tabi ojukòkoro, ki…

  • Efesu 6

    Ọmọ ati Òbí 1 ẸNYIN ọmọ, ẹ mã gbọ ti awọn õbi nyin ninu Oluwa: nitoripe eyi li o tọ́. 2 Bọ̀wọ fun baba ati iya rẹ (eyi ti iṣe ofin ikini pẹlu ileri), 3 Ki o le dara fun ọ, ati ki iwọ ki o le wà pẹ li aiye. 4 Ati ẹnyin baba,…

  • Galatia 1

    Ìkíni 1 PAULU, Aposteli (ki iṣe lati ọdọ enia wá, tabi nipa enia, ṣugbọn nipa Jesu Kristi, ati Ọlọrun Baba, ẹniti o jí i dide kuro ninu okú), 2 Ati gbogbo awọn arakunrin ti o wà pẹlu mi, si awọn ijọ Galatia: 3 Ore-ọfẹ si nyin ati alafia lati ọdọ Ọlọrun Baba wá, ati Jesu…

  • Galatia 2

    Àwọn Aposteli Yòókù Gba Paulu Bí Aposteli 1 LẸHIN ọdún mẹrinla, nigbana ni mo tún gòke lọ si Jerusalemu pẹlu Barnaba, mo si mu Titu lọ pẹlu mi. 2 Mo si gòke lọ nipa ifihan, mo si gbe ihinrere na kalẹ niwaju wọn ti mo nwasu larin awọn Keferi, ṣugbọn nikọ̀kọ fun awọn ti o…

  • Galatia 3

    Òfin tabi Igbagbọ 1 ẸNYIN alaironu ara Galatia, tani ha tàn nyin jẹ, ki ẹnyin ki o máṣe gbà otitọ gbọ́, li oju ẹniti a fi Jesu Kristi hàn gbangba lãrin nyin li ẹniti a kàn mọ agbelebu. 2 Kìki eyi ni mo fẹ mọ̀ lọwọ nyin pe, Nipa iṣẹ ofin li ẹnyin gbà Ẹmí…

  • Galatia 4

    1 NJẸ mo wipe, niwọn igbati arole na ba wà li ewe, kò yàtọ ninu ohunkohun si ẹrú bi o tilẹ jẹ oluwa ohun gbogbo; 2 Ṣugbọn o wà labẹ olutọju ati iriju titi fi di akokò ti baba ti yàn tẹlẹ. 3 Gẹgẹ bẹ̃ si li awa, nigbati awa wà li ewe, awa wà…

  • Galatia 5

    Òmìnira Onigbagbọ 1 NITORINA ẹ duro ṣinṣin ninu omnira na eyi ti Kristi fi sọ wa di omnira, ki ẹ má si ṣe tún fi ọrùn bọ àjaga ẹrú mọ́. 2 Kiyesi i, emi Paulu li o wi fun nyin pe, bi a ba kọ nyin nila, Kristi ki yio li ère fun nyin li…

  • Galatia 6

    Ẹ Máa Ran Ara Yín Lọ́wọ́ 1 ARÁ, bi a tilẹ mu enia ninu iṣubu kan, ki ẹnyin ti iṣe ti Ẹmí ki o mu irú ẹni bẹ̃ bọ̀ sipò ni ẹmí iwa tutu; ki iwọ tikararẹ mã kiyesara, ki a má ba dan iwọ nã wò pẹlu. 2 Ẹ mã rù ẹrù ọmọnikeji nyin,…

  • 2rd Korinti 1

    Ìkíni 1 PAULU Aposteli Jesu Kristi nipa ifẹ Ọlọrun, ati Timotiu arakunrin wa, si ijọ Ọlọrun ti o wà ni Korinti, pẹlu, gbogbo awọn enia mimọ́ ti o wà ni gbogbo Akaia: 2 Õre-ọfẹ si nyin ati alafia lati ọdọ Ọlọrun Baba wa, ati Jesu Kristi Oluwa. Ọpẹ́ lẹ́yìn ìjìyà 3 Olubukún li Ọlọrun, ati…

  • 2rd Korinti 2

    1 ṢUGBỌN mo ti pinnu eyi ninu emi tikarami pe, emi kì yio tun fi ibinujẹ tọ̀ nyin wá. 2 Nitoripe bi emi ba mu inu nyin bajẹ, njẹ tali ẹniti o si nmu inu mi dùn, bikoṣe ẹniti mo ti bà ninu jẹ? 3 Emi si kọwe nitori eyi kanna si nyin pe, nigbati…

  • 2rd Korinti 3

    Òjíṣẹ́ Majẹmu Titun 1 AWA ha tún bẹ̀rẹ lati mã yìn ara wa bi? tabi awa ha nfẹ iwe iyìn sọdọ nyin, tabi lati ọdọ nyin bi awọn ẹlomiran? 2 Ẹnyin ni iwe wa, ti a ti kọ si wa li ọkàn, ti gbogbo enia ti mọ̀, ti nwọn sì ti kà: 3 Bi a…

  • 2rd Korinti 4

    Ìṣúra ti Ẹ̀mí Ninu ìkòkò Amọ̀ 1 NITORINA bi awa ti ni iṣẹ-iranṣẹ yi, gẹgẹ bi a ti ri ãnu gbà, ãrẹ̀ kò mu wa; 2 Ṣugbọn awa ti kọ̀ gbogbo ohun ìkọkọ ti o ni itiju silẹ, awa kò rìn li ẹ̀tan, bẹ̃li awa kò fi ọwọ́ ẹ̀tan mu ọ̀rọ Ọlọrun; ṣugbọn nipa fifi…

  • 2rd Korinti 5

    1 NITORI awa mọ̀ pe, bi ile agọ́ wa ti aiye bá wó, awa ni ile kan lati ọdọ Ọlọrun, ile ti a kò fi ọwọ́ kọ́, ti aiyeraiye ninu awọn ọrun. 2 Nitori nitõtọ awa nkerora ninu eyi, awa si nfẹ gidigidi lati fi ile wa lati ọrun wá wọ̀ wa: 3 Bi o…

  • 2rd Korinti 6

    1 NJẸ bi alabaṣiṣẹpọ pẹlu rẹ̀, awa mbẹ̀ nyin ki ẹ máṣe gbà ore-ọfẹ Ọlọrun lasan. 2 (Nitori o wipe, emi ti gbohùn rẹ li akokò itẹwọgbà, ati li ọjọ igbala ni mo si ti ràn ọ lọwọ: kiyesi i, nisisiyi ni akokò itẹwọgbà; kiyesi i, nisisiyi ni ọjọ igbala.) 3 A kò si ṣe…

  • 2rd Korinti 7

    1 NITORINA, ẹnyin olufẹ, bi a ti ni ileri wọnyi, ẹ jẹ ki a wẹ̀ ara wa mọ́ kuro ninu gbogbo ẹgbin ti ara ati ti ẹmí, ki a mã sọ ìwa mimọ́ di pipé ni ìbẹru Ọlọrun. Inú Paulu Dùn Nígbà Tí Ìjọ Ronupiwada 2 Ẹ gbà wa tọkàntọkàn; a kò fi ibi ṣe…

  • 2rd Korinti 8

    Àwọn Onigbagbọ Ará Masedonia Lawọ́ 1 PẸLUPẸLU, ará, awa nsọ fun nyin niti ore-ọfẹ Ọlọrun, ti a fifun awọn ijọ Makedonia; 2 Bi o ti jẹ pe ninu ọpọ idanwò ipọnju, ọ̀pọlọpọ ayọ̀ wọn ati ibu aini wọn di pipọ si ọrọ̀ ilawọ wọn, 3 Nitori mo jẹri pe gẹgẹ bi agbara wọn, ani ju…

  • 2rd Korinti 9

    Ọrẹ fún Àwọn Onigbagbọ 1 NITORI nipa ti ipinfunni fun awọn enia mimọ́, kò ni pe mo nkọwe si nyin ju bẹ̃ lọ. 2 Nitori mo mọ̀ imura-tẹlẹ nyin, eyiti mo fi yangàn fun awọn ara Makedonia nitori nyin, pe, Akaia ti mura tan niwọn ọdún kan ti o kọja; itara nyin si ti rú…

  • 2rd Korinti 10

    Paulu Gbèjà Ara Rẹ̀ 1 ṢUGBỌN emi Paulu tikarami fi inu tutù ati ìwa pẹlẹ Kristi bẹ̀ nyin, emi ẹni irẹlẹ loju nyin nigbati mo wà larin nyin, ṣugbọn nigbati emi kò si, mo di ẹni igboiya si nyin. 2 Ṣugbọn emi bẹ̀ nyin pe ki o máṣe nigbati mo wà larin nyin ni mo…

  • 2rd Korinti 11

    Paulu ati Àwọn Aposteli Èké 1 ẸNYIN iba gbà mi diẹ ninu wère mi: ati nitotọ, ẹ gbà mi. 2 Nitoripe emi njowú lori nyin niti owú ẹni ìwa-bi-Ọlọrun: nitoriti mo ti fi nyin fun ọkọ kan, ki emi ki o le mu nyin wá bi wundia ti o mọ́ sọdọ Kristi. 3 Ṣugbọn ẹru…

  • 2rd Korinti 12

    Àwọn Ìran Tí Paulu Rí 1 EMI ko le ṣe aiṣogo bi kò tilẹ ṣe anfani. Nitori emi ó wá si iran ati iṣipaya Oluwa. 2 Emi mọ̀ ọkunrin kan ninu Kristi ni ọdún mẹrinla sẹhin, (yala ninu ara ni, emi kò mọ̀; tabi lati ara kuro ni, emi kò mọ̀; Ọlọrun ni o mọ):…

  • 2rd Korinti 13

    Ìkìlọ̀ Ìgbẹ̀yìn 1 EYI li o di igba kẹta ti emi ntọ̀ nyin wá. Li ẹnu ẹlẹri meji tabi mẹta li a o fi idi ọ̀rọ gbogbo mulẹ. 2 Mo ti sọ fun nyin ṣaju, mo si nsọ fun nyin tẹlẹ, bi ẹnipe mo wà pẹlu nyin nigba keji, ati bi emi kò ti si…

  • 1th Korinti 1

    Ìkíni 1 PAULU, ẹniti a pè lati jẹ Aposteli Jesu Kristi nipa ifẹ Ọlọrun, ati Sostene arakunrin, 2 Si ijọ enia Ọlọrun ti o wà ni Korinti, awọn ti a sọ di mimọ́ ninu Kristi Jesu, awọn ẹniti a npè li enia mimọ́, pẹlu gbogbo awọn ti npè orukọ Jesu Kristi Oluwa wa nibigbogbo, ẹniti…

  • 1th Korinti 2

    Paulu Ń Waasu Kristi Tí Wọ́n Kàn Mọ́ Agbelebu 1 ATI emi, ará, nigbati mo tọ̀ nyin wá, kì iṣe ọ̀rọ giga ati ọgbọ́n giga ni mo fi tọ̀ nyin wá, nigbati emi nsọ̀rọ ohun ijinlẹ Ọlọrun fun nyin. 2 Nitori mo ti pinnu rẹ̀ pe, emi kì yio mọ̀ ohunkohun larin nyin, bikoṣe Jesu…

  • 1th Korinti 3

    Alábàáṣiṣẹ́pọ̀ pẹlu Ọlọrun 1 ARÁ, emi kò si le ba nyin sọ̀rọ bi awọn ti iṣe ti Ẹmí, bikoṣe bi awọn ti iṣe ti ara, ani bi awọn ọmọ-ọwọ ninu Kristi. 2 Wàra ni mo ti fi bọ́ nyin, kì iṣe onjẹ: nitori ẹ kò iti le gbà a, nisisiyi na ẹ kò iti le…

  • 1th Korinti 4

    Iṣẹ́ Àwọn Aposteli 1 JẸ ki enia ki o ma kà wa bẹ̃ bi iranṣẹ Kristi, ati iriju awọn ohun ijinlẹ Ọlọrun. 2 Pẹlupẹlu a mbere lọwọ iriju pe ki oluwarẹ̀ na ki o jẹ olõtọ. 3 Ṣugbọn, ohun kikini ni fun mi pe, ki ẹ mã ṣe idajọ mi, tabi ki a mã ṣe…

  • 1th Korinti 5

    Paulu Ṣe Ìdájọ́ Lórí Ìwà Ìbàjẹ́ 1 A nròhin rẹ̀ kalẹ pe, àgbere wà larin nyin, ati irú àgbere ti a kò tilẹ gburo rẹ̀ larin awọn Keferi, pe ẹnikan ninu nyin fẹ aya baba rẹ̀. 2 Ẹnyin si nfẹ̀ soke, ẹnyin kò kuku kãnu ki a le mu ẹniti o hu iwa yi kuro…

  • 1th Korinti 6

    Onigbagbọ Ń Pe Ara Wọn Lẹ́jọ́ Níwájú Àwọn Alaigbagbọ 1 ẸNIKẸNI ninu nyin, ti o ni ọ̀ran kan si ẹnikeji rẹ̀, ha gbọdọ lọ pè e li ẹjọ niwaju awọn alaiṣõtọ, ki o má si jẹ niwaju awọn enia mimọ́? 2 Ẹnyin kò ha mọ̀ pe awọn enia mimọ́ ni yio ṣe idajọ aiye? Njẹ…

  • 1th Korinti 7

    Èrò Nípa Igbeyawo 1 NJẸ niti awọn ohun ti ẹ ti kọwe: O dara fun ọkunrin ki o má fi ọwọ kàn obinrin. 2 Ṣugbọn nitori àgbere, ki olukuluku ki o ni aya tirẹ̀, ati ki olukuluku ki o si ni ọkọ tirẹ̀. 3 Ki ọkọ ki o mã ṣe ohun ti o yẹ si…

  • 1th Korinti 8

    Oúnjẹ Tí A Fi Rúbọ fún Oriṣa 1 ṢUGBỌN niti awọn nkan ti a fi rubọ si oriṣa, a mọ̀ pe gbogbo wa li o ni ìmọ. Ìmọ a mã fẹ̀, ṣugbọn ifẹ ni gbe-ni-ro. 2 Bi ẹnikan ba si rò pe on mọ̀ ohun kan, kò ti imọ̀ bi o ti yẹ ti iba…

  • 1th Korinti 9

    Iṣẹ́ ati Ẹ̀tọ́ Aposteli 1 APOSTELI kọ́ emi iṣe bi? emi kò ha wà li omnira? emi ko ti ri Jesu Kristi Oluwa wa? iṣẹ mi kọ́ ẹnyin iṣe ninu Oluwa? 2 Bi emi ki iṣe Aposteli fun awọn ẹlomiran, ṣugbọn dajudaju Aposteli li emi iṣe fun nyin: nitori èdidi iṣẹ Aposteli mi li ẹnyin…

  • 1th Korinti 10

    Ìkìlọ̀ Nípa Ìbọ̀rìṣà 1 NITORI emi kò fẹ ki ẹnyin ki o ṣe alaimọ̀, ara, bi gbogbo awọn baba wa ti wà labẹ awọsanma, ti gbogbo wọn si là okun já; 2 Ti a si baptisi gbogbo wọn si Mose ninu awọsanma ati ninu okun; 3 Ti gbogbo wọn si ti jẹ onjẹ ẹmí kanna;…

  • 1th Korinti 11

    1 Ẹ mã ṣe afarawe mi, ani gẹgẹ bi emi ti nṣe afarawe Kristi. Obinrin Ní láti Bo Orí Ninu Ìsìn 2 Njẹ, ará, mo yìn nyin ti ẹnyin nranti mi ninu ohun gbogbo, ti ẹnyin ti di ẹ̀kọ́ wọnni mu ṣinṣin, ani gẹgẹ bi mo ti fi wọn le nyin lọwọ. 3 Ṣugbọn mo…

  • 1th Korinti 12

    Àwọn Ẹ̀bùn Ẹ̀mí Mímọ́ 1 NJẸ niti ẹbun ẹmí, ará, emi kò fẹ ki ẹnyin ki o jẹ ope. 2 Ẹnyin mọ̀ pe nigbati ẹnyin jẹ Keferi, a fà nyin lọ sọdọ awọn odi oriṣa, lọnakọna ti a fa nyin. 3 Nitorina mo fẹ ki ẹ mọ̀ pe, kò si ẹniti nsọ̀rọ nipa Ẹmí Ọlọrun…

  • 1th Korinti 13

    1 BI mo tilẹ nfọ oniruru ede ati ti angẹli, ti emi kò si ni ifẹ, emi dabi idẹ ti ndún, tabi bi kimbali olohùn goro. 2 Bi mo si ni ẹbun isọtẹlẹ, ti mo si ni oye gbogbo ohun ijinlẹ, ati gbogbo ìmọ; bi mo si ni gbogbo igbagbọ́, tobẹ̃ ti mo le ṣí…

  • 1th Korinti 14

    Ẹ̀bùn Èdè Àjèjì ati Ti Ìsọtẹ́lẹ̀ 1 Ẹ mã lepa ifẹ, ki ẹ si mã fi itara ṣafẹri ẹ̀bun ti iṣe ti Ẹmí, ṣugbọn ki ẹ kuku le mã sọtẹlẹ. 2 Nitori ẹniti nsọ̀rọ li ède aimọ̀, kò bá enia sọ̀rọ bikoṣe Ọlọrun: nitori kò si ẹniti o gbọ; ṣugbọn nipa ti Ẹmí o nsọ…

  • 1th Korinti 15

    Ajinde Kristi 1 NJẸ, ará, emi nsọ ihinrere na di mimọ̀ fun nyin ti mo ti wãsu fun nyin, eyiti ẹnyin pẹlu ti gbà, ninu eyi ti ẹnyin si duro; 2 Nipaṣe eyiti a fi ngbà nyin là pẹlu, bi ẹnyin ba di ọ̀rọ ti mo ti wãsu fun nyin mú ṣinṣin, bikoṣepe ẹnyin ba…

  • 1th Korinti 16

    Ìtọrẹ Onigbagbọ 1 NJẸ niti idawo fun awọn enia mimọ́, bi mo ti fi aṣẹ fun awọn ijọ Galatia, bẹ̃ gẹgẹ ni ki ẹ ṣe. 2 Li ọjọ ikini ọ̀sẹ, ki olukuluku nyin fi sinu iṣura lọdọ ara rẹ̀ li apakan, gẹgẹ bi Ọlọrun ti ṣe rere fun u, ki o máṣe si ikojọ nigbati…

  • Romu 1

    Ìkíni 1 PAULU, iranṣẹ Jesu Kristi, ti a pè lati jẹ aposteli, ti a yà sọ̀tọ fun ihinrere Ọlọrun, 2 (Ti o ti ṣe ileri tẹlẹ rí ninu iwe-mimọ́, lati ọwọ awọn woli rẹ̀), 3 Niti Ọmọ rẹ̀, ti a bí lati inu irú-ọmọ Dafidi nipa ti ara, 4 Ẹniti a pinnu rẹ̀ lati jẹ…

  • Romu 2

    Ìdájọ́ Òdodo Tí Ọlọrun Ṣe 1 NITORINA alairiwi ni iwọ ọkunrin na, ẹnikẹni ti o wù ki o jẹ ti ndajọ: nitori ninu ohun ti iwọ nṣe idajọ ẹlomiran, iwọ ndá ara rẹ lẹbi; nitori iwọ ti ndajọ nṣe ohun kanna. 2 Ṣugbọn awa mọ̀ pe idajọ Ọlọrun jẹ gẹgẹ bi otitọ si gbogbo awọn…

  • Romu 3

    1 NJẸ anfani ki ha ni ti Ju? tabi kini ère ilà kíkọ? 2 Pipọ lọna gbogbo; ekini, nitoripe awọn li a fi ọ̀rọ Ọlọrun le lọwọ. 3 Njẹ ki ha ni bi awọn kan jẹ alaigbagbọ́? aigbagbọ́ wọn yio ha sọ otitọ Ọlọrun di asan bi? 4 Ki a má ri: k’Ọlọrun jẹ olõtọ,…

  • Romu 4

    Àpẹẹrẹ Abrahamu 1 NJẸ kili awa o ha wipe Abrahamu, baba wa nipa ti ara, ri? 2 Nitori bi a ba da Abrahamu lare nipa iṣẹ, o ni ohun iṣogo; ṣugbọn kì iṣe niwaju Ọlọrun. 3 Iwe-mimọ́ ha ti wi? Abrahamu gbà Ọlọrun gbọ́, a si kà a si ododo fun u. 4 Njẹ fun…

  • Romu 5

    Àyọrísí Ìdáláre 1 NJẸ bi a si ti nda wa lare nipa igbagbọ́, awa ni alafia lọdọ Ọlọrun nipa Oluwa wa Jesu Kristi: 2 Nipasẹ ẹniti awa si ti ri ọ̀na gbà nipa igbagbọ́ si inu ore-ọfẹ yi ninu eyi ti awa gbé duro, awa si nyọ̀ ni ireti ogo Ọlọrun. 3 Kì si iṣe…

  • Romu 6

    Ikú sí Ẹ̀ṣẹ̀, Ìyè ninu Kristi 1 NJẸ awa o ha ti wi? Ki awa ki o ha joko ninu ẹ̀ṣẹ, ki ore-ọfẹ ki o le ma pọ̀ si i? 2 Ki a má ri. Awa ẹniti o ti kú si ẹ̀ṣẹ, awa o ha ṣe wà lãye ninu rẹ̀ mọ́? 3 Tabi ẹ kò…

  • Romu 7

    Àpẹẹrẹ Láti Inú Igbeyawo 1 TABI ẹnyin ha ṣe alaimọ̀, ará (nitori awọn ti o mọ̀ ofin li emi mba sọrọ), pe ofin ni ipa lori enia niwọn igbati o ba wà lãye? 2 Nitori obinrin ti o ni ọkọ, ìwọn igbati ọkọ na wà lãye, a fi ofin dè e mọ́ ọkọ na; ṣugbọn…

  • Romu 8

    Ìgbésí-Ayé Onigbagbọ Ninu Ẹ̀mí 1 NJẸ ẹbi kò si nisisiyi fun awọn ti o wà ninu Kristi Jesu, awọn ti kò rìn nipa ti ara, bikoṣe nipa ti Ẹmí. 2 Nitori ofin Ẹmí ìye ninu Kristi Jesu ti sọ mi di omnira lọwọ ofin ẹ̀ṣẹ ati ti ikú. 3 Nitori ohun ti ofin kò le…

  • Romu 9

    Ọlọrun Yan Israẹli 1 OTITỌ li emi nsọ ninu Kristi, emi kò ṣeke, ọkàn mi si njẹ mi li ẹrí ninu Ẹmí Mimọ́, 2 Pe mo ni ibinujẹ pupọ, ati ikãnu igbagbogbo li ọkàn mi. 3 Nitori mo fẹrẹ le gbadura pe ki a ké emi tikarami kuro lọdọ Kristi, nitori awọn ará mi, awọn…

  • Romu 10

    1 ARÁ, ifẹ ọkàn mi ati adura mi si Ọlọrun fun Israeli ni, fun igbala wọn. 2 Nitori mo gbà ẹri wọn jẹ pe, nwọn ni itara fun Ọlọrun, ṣugbọn kì iṣe gẹgẹ bi ìmọ. 3 Nitori bi nwọn kò ti mọ ododo Ọlọrun, ti nwọn si nwá ọna lati gbé ododo ara wọn kalẹ,…

  • Romu 11

    Àánú Ọlọrun Fún Israẹli 1 NJẸ mo ni, Ọlọrun ha ta awọn enia rẹ̀ nù bi? Ki a má ri. Nitori Israeli li emi pẹlu, lati inu irú-ọmọ Abrahamu, li ẹ̀ya Benjamini. 2 Ọlọrun kò ta awọn enia rẹ̀ nù ti o ti mọ̀ tẹlẹ. Tabi ẹnyin kò mọ̀ bi iwe-mimọ́ ti wi niti Elijah?…

  • Romu 12

    Ayé Titun Ninu Kristi 1 NITORINA mo fi iyọ́nu Ọlọrun bẹ̀ nyin, ará, ki ẹnyin ki o fi ara nyin fun Ọlọrun li ẹbọ ãye, mimọ́, itẹwọgbà, eyi ni iṣẹ-isìn nyin ti o tọ̀na. 2 Ki ẹ má si da ara nyin pọ̀ mọ́ aiye yi: ṣugbọn ki ẹ parada lati di titun ni iro-inu…

  • Romu 13

    Ipò Àwọn Aláṣẹ Ìlú 1 KI olukuluku ọkàn ki o foribalẹ fun awọn alaṣẹ ti o wà ni ipo giga. Nitori kò si aṣẹ kan, bikoṣe lati ọdọ Ọlọrun wá: awọn alaṣẹ ti o si wà, lati ọdọ Ọlọrun li a ti làna rẹ̀ wá. 2 Nitorina ẹniti o ba tapá si aṣẹ, o tapá…

  • Romu 14

    Má Ṣe Dá Ẹnìkejì Rẹ Lẹ́jọ́ 1 ṢUGBỌN ẹniti o ba ṣe ailera ni igbagbọ́ ẹ gbà a, li aitọpinpin iṣiyemeji rẹ̀. 2 Ẹnikan gbagbọ́ pe on le mã jẹ ohun gbogbo: ẹlomiran ti o si ṣe alailera njẹ ewebẹ. 3 Ki ẹniti njẹ máṣe kẹgan ẹniti kò jẹ; ki ẹniti kò si jẹ ki…

  • Romu 15

    Ẹ Máa Ṣe Ohun Tí Ó Tẹ́ Ẹlòmíràn Lọ́rùn 1 NJẸ o yẹ ki awa ti o lera iba mã ru ẹrù ailera awọn alailera, ki a má si ṣe ohun ti o wù ara wa. 2 Jẹ ki olukuluku wa ki o mã ṣe ohun ti o wù ọmọnikeji rẹ̀ si rere rẹ̀ lati…

  • Romu 16

    Paulu Kí Ọpọlọpọ Eniyan Ninu Ìjọ Romu 1 MO fi Febe, arabinrin wa, le nyin lọwọ ẹniti iṣe diakoni ijọ ti o wà ni Kenkrea: 2 Ki ẹnyin le gbà a ninu Oluwa, bi o ti yẹ fun awọn enia mimọ́, ki ẹnyin ki o si ràn a lọwọ iṣẹkiṣẹ ti o nwá ni iranlọwọ…

  • Diamond-certified American hitmaker Post Malone bridges the gap between the worlds of rap and the pop mainstream.

    Diamond-certified American hitmaker Post Malone bridges the gap between the worlds of rap and the pop mainstream. Within five years of his debut, he went from underground genre novelty to certified superstar, amassing a string of Top Ten singles with a hybrid style that combined his unique vocal delivery, pained lyrics, and hip-hop production inspired…

    Diamond-certified American hitmaker Post Malone bridges the gap between the worlds of rap and the pop mainstream.
  • Lewis Capaldi returns with a comeback that’s both intimate and colossal. His new single “Survive” signals the next chapter—an anthem of resilience that reaffirms his place among the most powerful voices in modern music.

    With two record-breaking albums, billions of streams, and headline tours across five continents, his rise from small-town Scottish pubs to global arenas has captured hearts worldwide. His debut album Divinely Uninspired to a Hellish Extent introduced the world to his signature blend of raw vulnerability and unforgettable melodies, led by the international smash “Someone You…

    Lewis Capaldi returns with a comeback that’s both intimate and colossal. His new single “Survive” signals the next chapter—an anthem of resilience that reaffirms his place among the most powerful voices in modern music.
  • The Weeknd took over pop music & culture on his own terms filtering R&B, Pop,& hip-hop through an ambitious widescreen lens. The multi-platinum 4X GRAMMY Award winner has emerged as one of the most successful & significant artists of the modern era.

    The Weeknd took over pop music & culture on his own terms filtering R&B, Pop,& hip-hop through an ambitious widescreen lens. The multi-platinum 4X GRAMMY Award winner has emerged as one of the most successful & significant artists of the modern era. 2012’s 3X platinum Trilogy collated 3 breakout mixtapes—House of Balloons, Thursday & Echoes…

    The Weeknd took over pop music & culture on his own terms filtering R&B, Pop,& hip-hop through an ambitious widescreen lens. The multi-platinum 4X GRAMMY Award winner has emerged as one of the most successful & significant artists of the modern era.
  • Harry Styles’ third solo album, Harry’s House, is breaking new ground for one of the most creative forces in pop music, a star who keeps refusing to stand still. It’s a deeply personal statement from an artist who has never sounded this joyous

    Harry Styles’ third solo album, Harry’s House, is breaking new ground for one of the most creative forces in pop music, a star who keeps refusing to stand still. It’s a deeply personal statement from an artist who has never sounded this joyous, this confident, this fearless in facing the future. Harry’s House debuted at…

    Harry Styles’ third solo album, Harry’s House, is breaking new ground for one of the most creative forces in pop music, a star who keeps refusing to stand still. It’s a deeply personal statement from an artist who has never sounded this joyous
  • Idiosyncratic pop singer Ed Sheeran borrows from any style that crosses his path, molding genres to fit a musical character all his own that’s charming, personable, and popular on a global scale.

    When Ed Sheeran released +, he had just turned 20. He had been playing music since he was a child in Framlingham, Suffolk — he was born in Halifax, West Yorkshire but his family moved when he was young — enthralled by the classic rock he heard around the house. Sheeran started writing music in…

    Idiosyncratic pop singer Ed Sheeran borrows from any style that crosses his path, molding genres to fit a musical character all his own that’s charming, personable, and popular on a global scale.
  • Rapper and entertainer Cardi B draws from a seemingly never-ending supply of confidence, charisma, and evisceratingly sharp flows. She broke through in 2017 with her debut commercially released single, “Bodak Yellow,” topping the Billboard Hot 100 and becoming the first female rapper to do so in nearly two decades.

    Rapper and entertainer Cardi B draws from a seemingly never-ending supply of confidence, charisma, and evisceratingly sharp flows. She broke through in 2017 with her debut commercially released single, “Bodak Yellow,” topping the Billboard Hot 100 and becoming the first female rapper to do so in nearly two decades. Her 2018 debut studio album, Invasion…

    Rapper and entertainer Cardi B draws from a seemingly never-ending supply of confidence, charisma, and evisceratingly sharp flows. She broke through in 2017 with her debut commercially released single, “Bodak Yellow,” topping the Billboard Hot 100 and becoming the first female rapper to do so in nearly two decades.
  • Nicki Minaj’s unique combination of ferocity and humor and a rap style built on razor-sharp wordplay, mercilessly blunt lyricism.

    Nicki Minaj’s unique combination of ferocity and humor and a rap style built on razor-sharp wordplay, mercilessly blunt lyricism, and delivery that turns on a dime from sugary to snarling, has skyrocketed her from mixtape phenom to enduring global pop star. The rapper’s early days included attempts at an acting career and losing her job…

    Nicki Minaj’s unique combination of ferocity and humor and a rap style built on razor-sharp wordplay, mercilessly blunt lyricism.
  • Justin Bieber has quietly worked towards delivering a career-defining artistic statement with his 2025 seventh full-length album, SWAG via Def Jam Recordings.

    Since his emergence in 2008, Justin Bieber has quietly worked towards delivering a career-defining artistic statement with his 2025 seventh full-length album, SWAG via Def Jam Recordings. Beyond writing songs and performing, he co-produced the LP which is a 21-track opus evocative of his evolution, yet indicative of the signature spirit millions of fans first…

    Justin Bieber has quietly worked towards delivering a career-defining artistic statement with his 2025 seventh full-length album, SWAG via Def Jam Recordings.
  • Dj Khaled toiled as a disc jockey for years before he became an immensely successful, larger than life figure in rap music.

    No overnight success, DJ Khaled toiled as a disc jockey for years before he became an immensely successful, larger-than-life figure in rap music. Since the latter half of the 2000s, Khaled has factored into triumphant crossover singles that have seemed like events, charming fans with his fun-loving spirit, ebullient interjections, and well-placed talent that has…

    Dj Khaled toiled as a disc jockey for years before he became an immensely successful, larger than life figure in rap music.
  • 50 cent endured substantial obstacles throughout his young, yet remarkably dramatic life before becoming the most discussed figure in rap.

    Though he would later struggle with the nature of his fame as well as market expectations, 50 Cent endured substantial obstacles throughout his young yet remarkably dramatic life before becoming the most discussed figure in rap, if not pop music in general, circa 2003. Following an unsuccessful late-’90s run at mainstream success (foiled by an…

    50 cent endured substantial obstacles throughout his young, yet remarkably dramatic life before becoming the most discussed figure in rap.