-
Matteu 8
Adẹ́tẹ̀ kan Rí Ìwòsàn(Mak 1:40-45; Luk 5:12-16) 1 NIGBATI o ti ori òke sọkalẹ, ọ̀pọ enia ntọ̀ ọ lẹhin. 2 Si wò o, adẹtẹ̀ kan wá, o tẹriba fun u, o wipe, Oluwa, bi iwọ ba fẹ, iwọ le sọ mi di mimọ́. 3 Jesu si nà ọwọ́ rẹ̀, o fi bà a, o wipe,…
-
Matteu 9
Jesu Wo Arọ kan Sàn(Mak 2:1-12; Luk 5:17-26) 1 O si bọ sinu ọkọ̀, o rekọja, o si wá si ilu on tikararẹ̀. 2 Si kiyesi i, nwọn gbé ọkunrin kan ti o li ẹ̀gba wá sọdọ rẹ̀, o dubulẹ lori akete; nigbati Jesu ri igbagbọ́ wọn, o wi fun ẹlẹgba na pe, Ọmọkunrin, tújuka,…
-
Matteu 10
Jesu fún Àwọn Ọmọ-ẹ̀yìn Mejila Láṣẹ(Mak 3:13-19; Luk 6:12-16) 1 NIGBATI o si pè awọn ọmọ-ẹhin rẹ̀ mejejila si ọdọ, o fi agbara fun wọn lori awọn ẹmi aimọ́, lati ma lé wọn jade ati lati ṣe iwòsan gbogbo àrun ati gbogbo aisan. 2 Orukọ awọn aposteli mejila na ni wọnyi: Eyi ekini ni Simoni,…
-
Matteu 11
1 O si ṣe, nigbati Jesu pari aṣẹ rẹ̀ tan fun awọn ọmọ-ẹhin rẹ̀ mejejila, o ti ibẹ̀ rekọja lati ma kọni, ati lati ma wasu ni ilu wọn gbogbo. Johanu Onítẹ̀bọmi Ranṣẹ sí Jesu(Luk 7:18-35) 2 Nigbati Johanu gburo iṣẹ Kristi ninu tubu, o rán awọn ọmọ-ẹhin rẹ̀ meji, 3 O si wipe, Iwọ…
-
Matteu 12
Àwọn Ọmọ-ẹ̀yìn Jesu Ń Já Ọkà ní Ọjọ́ Ìsinmi(Mak 2:23-28; Luk 6:1-5) 1 LAKOKÒ na ni Jesu là ãrin oko ọkà lọ li ọjọ isimi; ebi si npa awọn ọmọ-ẹhin rẹ̀, nwọn si bẹ̀rẹ si ima ya ipẹ́ ọkà, nwọn si njẹ. 2 Ṣugbọn nigbati awọn Farisi ri i, nwọn wi fun u pe, Wò…
-
Matteu 13
Òwe Afunrugbin(Mak 4:1-9; Luk 8:4-8) 1 LI ọjọ kanna ni Jesu ti ile jade, o si joko leti okun. 2 Ọpọlọpọ enia pejọ sọdọ rẹ̀, tobẹ̃ ti o fi bọ sinu ọkọ̀, o joko; gbogbo enia si duro leti okun. 3 O si fi owe ba wọn sọ̀rọ ohun pipọ, o wipe, Wo o, afunrugbin…
-
Matteu 14
Ikú Johanu Onítẹ̀bọmi(Mak 6:14-29; Luk 9:7-9) 1 LI akokò na ni Herodu tetrarki gbọ́ okikí Jesu, 2 O si wi fun awọn ọmọ-ọdọ rẹ̀ pe, Johanu Baptisti li eyi; o jinde kuro ninu okú; nitorina ni iṣẹ agbara ṣe hàn lara rẹ̀. 3 Herodu sá ti mu Johanu, o dè e, o si fi i…
-
Matteu 15
Àṣà Ìbílẹ̀ Àwọn Juu(Mak 7:1-23) 1 NIGBANA li awọn akọwe ati awọn Farisi ti Jerusalemu tọ̀ Jesu wá, wipe, 2 Ẽṣe ti awọn ọmọ-ẹhin rẹ fi nrú ofin atọwọdọwọ awọn alàgba? nitoriti nwọn kì iwẹ̀ ọwọ́ wọn nigbati nwọn ba njẹun. 3 Ṣugbọn o dahùn, o si wi fun wọn pe, Ẽṣe ti ẹnyin pẹlu…
-
Matteu 16
Àwọn Juu ń Fẹ́ Àmì(Mak 8:11-13; Luk 12:54-56) 1 AWỌN Farisi pẹlu awọn Sadusi si wá, nwọn ndán a wò, nwọn si nfẹ ki o fi àmi hàn fun wọn lati ọrun wá. 2 Ṣugbọn o dahùn o si wi fun wọn pe, Nigbati ó ba di aṣalẹ, ẹnyin a wipe, Ọjọ ó dara: nitoriti…
-
Matteu 17
Jesu Para Dà(Mak 9:2-13; Luk 9:28-36) 1 LẸHIN ijọ mẹfa Jesu mu Peteru, ati Jakọbu, ati Johanu arakunrin rẹ̀, o si mu wọn wá sori òke giga li apakan, 2 Ara rẹ̀ si yipada niwaju wọn; oju rẹ̀ si nràn bi õrùn; aṣọ rẹ̀ si fún, o dabi imọle. 3 Si wo o, Mose ati…
-
Matteu 18
Ta ní Ṣe Pataki Jùlọ ní Ìjọba Ọ̀run?(Mak 9:33-37; Luk 9:46-48) 1 LAKOKÒ na li awọn ọmọ-ẹhin Jesu tọ̀ ọ wá, nwọn bi i pe, Tali ẹniti o pọ̀ju ni ijọba ọrun? 2 Jesu si pe ọmọ kekere kan sọdọ rẹ̀, o mu u duro larin wọn, 3 O si wipe, Lõtọ ni mo wi…
-
Matteu 19
Ẹ̀kọ́ nípa Ipò Ọkọ ati Aya sí Ara Wọn(Mak 10:1-12) 1 O si ṣe, nigbati Jesu pari ọ̀rọ wọnyi tan, o kuro ni Galili, o si lọ si ẹkùn Judea li oke odò Jordani. 2 Ọpọ ijọ enia si tọ̀ ọ lẹhin, o si mu wọn larada nibẹ̀. 3 Awọn Farisi si wá sọdọ rẹ̀,…
-
Matteu 20
Àwọn Òṣìṣẹ́ ninu Ọgbà Àjàrà 1 IJỌBA ọrun sá dabi ọkunrin kan ti iṣe bãle ile, ti o jade ni kutukutu owurọ lati pè awọn alagbaṣe sinu ọgba ajara rẹ̀. 2 Nigbati o si ba awọn alagbaṣe pinnu rẹ̀ si owo idẹ kọkan li õjọ, o rán wọn lọ sinu ọgba ajara rẹ̀. 3 O…
-
Matteu 21
Jesu Fi Ẹ̀yẹ Wọ Jerusalẹmu(Mak 11:1-11; Luk 19:28-38; Joh 12:12-19) 1 NIGBATI nwọn sunmọ eti Jerusalemu, ti nwọn de Betfage li òke Olifi, nigbana ni Jesu rán awọn ọmọ-ẹhin rẹ̀ meji lọ. 2 O wi fun wọn pe, Ẹ lọ si iletò ti o kọju si nyin, lọgan ẹnyin o ri kẹtẹkẹtẹ kan ti a…
-
Matteu 22
Òwe Àsè Igbeyawo(Luk 14:15-24) 1 Jesu si dahùn, o si tún fi owe sọ̀rọ fun wọn pe, 2 Ijọba ọrun dabi ọba kan, ti o ṣe igbeyawo fun ọmọ rẹ̀. 3 O si rán awọn ọmọ-ọdọ rẹ̀ lọ ipè awọn ti a ti pè tẹlẹ si ibi iyawo: ṣugbọn nwọn kò fẹ wá. 4 O…
-
Matteu 23
Jesu Bá Àwọn Amòfin ati Àwọn Farisi Wí(Mak 12:38-39; Luk 11:43, 46; 20:45-46) 1 NIGBANA ni Jesu wi fun ijọ enia, ati awọn ọmọ-ẹhin rẹ̀, 2 Pe, Awọn akọwe pẹlu awọn Farisi joko ni ipò Mose: 3 Nitorina ohunkohun gbogbo ti nwọn ba wipe ki ẹ kiyesi, ẹ mã kiyesi wọn ki ẹ si mã…
-
Matteu 24
Jesu Sọtẹ́lẹ̀ nípa Wíwó Tẹmpili(Mak 13:1-2; Luk 21:5-6) 1 JESU si jade lọ, o ti tẹmpili kuro: awọn ọmọ-ẹhin rẹ̀ si tọ̀ ọ wá lati fi kikọ́ tẹmpili hàn a. 2 Jesu si wi fun wọn pe, Ẹnyin kò ri gbogbo nkan wọnyi? lõtọ ni mo wi fun nyin, Kì yio si okuta kan nihinyi…
-
Matteu 25
Òwe nípa Àwọn Wundia Mẹ́wàá 1 NIGBANA li a o fi ijọba ọrun wé awọn wundia mẹwa, ti o mu fitila wọn, ti nwọn si jade lọ ipade ọkọ iyawo. 2 Marun ninu wọn ṣe ọlọgbọn, marun si ṣe alaigbọn. 3 Awọn ti o ṣe alaigbọ́n mu fitila wọn, nwọn kò si mu oróro lọwọ:…
-
Matteu 26
Àwọn Juu dìtẹ̀ láti pa Jesu(Mak 14:1-2; Luk 22:1-2; Joh 11:45-53) 1 O SI ṣe, nigbati Jesu pari gbogbo ọ̀rọ wọnyi, o wi fun awọn ọmọ-ẹhin rẹ̀ pe, 2 Ẹnyin mọ̀ pe lẹhin ọjọ meji ni ajọ irekọja, a o si fi Ọmọ-enia le ni lọwọ, lati kàn a mọ agbelebu. 3 Nigbana li awọn…
-
Matteu 27
Wọ́n fa Jesu lọ sọ́dọ̀ Pilatu(Mak 15:1; Luk 23:1-2; Joh 18:28-32) 1 NIGBATI o di owurọ̀, gbogbo awọn olori alufa ati awọn àgbãgba gbìmọ si Jesu lati pa a: 2 Nigbati nwọn si dè e tan, nwọn mu u lọ, nwọn si fi i le Pontiu Pilatu lọwọ ti iṣe Bãlẹ. Ikú Judasi(A. Apo 1:18-19)…
-
Matteu 28
Ajinde Jesu(Mak 16:1-10; Luk 24:1-12; Joh 20:1-10) 1 LI opin ọjọ isimi, bi ilẹ ọjọ kini ọ̀sẹ ti bèrẹ si imọ́, Maria Magdalene ati Maria keji wá lati wò ibojì na. 2 Si wò o, ìṣẹlẹ nla ṣẹ̀: nitori angẹli Oluwa ti ọrun sọkalẹ wá, o si yi okuta na kuro, o si joko le…
-
STD tests means Sexually Transmitted Disease tests.
STD tests means Sexually Transmitted Disease tests. They are medical tests used to check if someone has an infection that can be passed through sexual contact. In simple terms: STD tests help doctors find out whether a person has an infection like:HIVGonorrheaChlamydiaSyphilisHepatitis B or C(and others) Why people do STD tests:To know their health statusTo…
-
Malaki 1
1 Ọ̀RỌ-ÌMỌ ọ̀rọ Oluwa si Israeli nipa ọwọ Malaki. Ìfẹ́ OLUWA sí Israẹli 2 Emi ti fẹ nyin, li Oluwa wi. Ṣugbọn ẹnyin wipe, Ninu kili o fẹ wa? Arakunrin Jakobu ki Esau iṣe? li Oluwa wi: bẹli emi sa fẹ Jakobu, 3 Mo si korira Esau, mo si sọ awọn oke-nla rẹ̀ ati ilẹ…
-
Malaki 2
1 NJẸ nisisiyi, ẹnyin alufa, ofin yi ni fun nyin. 2 Bi ẹnyin kì o ba gbọ́, ti ẹnyin kì o ba fi si aiya, lati fi ogo fun orukọ mi, li Oluwa awọn ọmọ-ogun wi; emi o si rán egún si ori nyin, emi o si fi ibukun nyin ré, lõtọ mo ti fi…
-
Malaki 3
1 KIYESI i, Emi o rán onṣẹ mi, yio si tún ọ̀na ṣe niwaju mi: ati Oluwa, ti ẹnyin nwá, yio de li ojijì si tempili rẹ̀, ani onṣẹ majẹmu na, ti inu nyin dùn si; kiye si i, o mbọ̀ wá, li Oluwa awọn ọmọ-ogun wi. 2 Ṣugbọn tali o le gbà ọjọ wíwa…
-
Malaki 4
Ọjọ́ OLUWA ń bọ̀ 1 SA kiye si i, ọjọ na mbọ̀, ti yio ma jó bi iná ileru; ati gbogbo awọn agberaga, ati gbogbo awọn oluṣe buburu yio dabi akékù koriko: ọjọ na ti mbọ̀ yio si jo wọn run, li Oluwa awọn ọmọ-ogun wi, ti kì yio fi kù gbòngbo tabi ẹka fun…
-
Sakaria 1
OLUWA Pe Àwọn Eniyan Rẹ̀ Pada Sọ́dọ̀ 1 LI oṣù kẹjọ, li ọdun keji Dariusi, li ọ̀rọ Oluwa tọ̀ Sekariah wá, ọmọ Berekiah ọmọ Iddo woli, pe, 2 Oluwa ti binu pupọ̀ si awọn baba nyin. 3 Nitorina iwọ wi fun wọn pe, Bayi li Oluwa awọn ọmọ-ogun wi; Oluwa awọn ọmọ-ogun wipe, Ẹ yipadà…
-
Sakaria 2
Ìran nípa Okùn Ìwọ̀n 1 MO si tun gbe oju mi soke, mo si wò, si kiyesi i, ọkunrin kan ti on ti okùn-iwọ̀n lọwọ rẹ̀. 2 Mo si wipe, Nibo ni iwọ nlọ? o si wi fun mi pe, Lati wọ̀n Jerusalemu, lati ri iye ibú rẹ̀, ati iye gigùn rẹ̀. 3 Si kiyesi…
-
Sakaria 3
Ìran wolii náà nípa Olórí Àlùfáà 1 O sì fi Joṣua olori alufa hàn mi, o duro niwaju angeli Oluwa, Satani si duro lọwọ ọtun rẹ̀ lati kọju ijà si i. 2 Oluwa si wi fun Satani pe, Oluwa ba ọ wi, iwọ Satani; ani Oluwa ti o ti yàn Jerusalemu, o ba ọ wi:…
-
Sakaria 4
Ìran nípa Ọ̀pá Fìtílà 1 ANGELI ti o mba mi sọ̀rọ si tún de, o si ji mi, bi ọkunrin ti a ji lati oju orun rẹ̀, 2 O si wi fun mi pe, Kini iwọ ri? Mo si wipe, mo wò, si kiyesi i, ọ̀pa fitilà ti gbogbo rẹ̀ jẹ wurà, pẹlu kòjo rẹ̀…
-
Sakaria 5
Ìran nípa Ìwé Kíká Tí Ó Ń Fò 1 NIGBANA ni mo yipadà, mo si gbe oju mi soke, mo si wò, si kiyesi i, iwe-kiká ti nfò. 2 O si wi fun mi pe, Kini iwọ ri? Emi si dahùn pe, mo ri iwe-kiká ti nfò; gigùn rẹ̀ jẹ ogún igbọnwọ, ibú rẹ̀ si…
-
Sakaria 6
Ìran nípa Àwọn Kẹ̀kẹ́ Ogun Mẹrin 1 MO si yipadà, mo si gbe oju mi soke, mo si wò, si kiyesi i, kẹkẹ́ mẹrin jade wá lati ãrin oke-nla meji; awọn oke-nla na si jẹ oke-nla idẹ. 2 Awọn ẹṣin pupa wà ni kẹkẹ́ ekini; ati awọn ẹṣin dudu ni kẹkẹ́ keji; 3 Ati awọn…
-
Sakaria 7
OLUWA Kọ Ààwẹ̀ Àgàbàgebè 1 O si ṣe li ọdun kẹrin Dariusi ọba, ọ̀rọ Oluwa tọ̀ Sekariah wá ni ijọ kẹrin oṣù kẹsan, Kislefi; 2 Nigbati nwọn rán Ṣereṣeri ati Regemmeleki, ati awọn enia wọn si ile Ọlọrun lati wá oju rere Oluwa. 3 Ati lati bá awọn alufa ti o wà ni ile Oluwa…
-
Sakaria 8
Ọlọrun ṣèlérí láti Dá Ibukun Jerusalẹmu Pada 1 Ọ̀RỌ Oluwa awọn ọmọ-ogun si tun tọ̀ mi wá, wipe, 2 Bayi li Oluwa awọn ọmọ-ogun wi; owu nlanla ni mo jẹ fun Sioni, ikannu nlanla ni mo fi jowu fun u. 3 Bayi li Oluwa wi; Mo ti yipada si Sioni emi o si gbe ãrin…
-
Sakaria 9
Ìdájọ́ lórí Àwọn Orílẹ̀-Èdè Tí Wọ́n Yí Israẹli Ká 1 Ọ̀RỌ-ÌMỌ ọ̀rọ Oluwa ni ilẹ Hadraki, Damasku ni yio si jẹ ibi isimi rẹ̀: nitori oju Oluwa mbẹ lara enia, ati lara gbogbo ẹ̀ya Israeli. 2 Ati Hamati pẹlu yio ṣe ãla rẹ̀: Tire ati Sidoni bi o tilẹ ṣe ọlọgbọ́n gidigidi. 3 Tire si…
-
Sakaria 10
OLUWA Ṣèlérí láti Gba Àwọn Eniyan Rẹ̀ Là 1 Ẹ bère òjo nigba arọ̀kuro li ọwọ Oluwa; Oluwa yio kọ mànamána, yio si fi ọ̀pọ òjò fun wọn, fun olukulukù koriko ni pápa. 2 Nitori awọn oriṣa ti nsọ̀rọ asan, awọn alafọṣẹ si ti ri eké, nwọn si ti rọ́ alá eké; nwọn ntù ni…
-
Sakaria 11
Ìṣubú Àwọn Aninilára 1 ṢI ilẹkun rẹ wọnni silẹ, Iwọ Lebanoni, ki iná ba le jẹ igi kedari rẹ run. 2 Hu, igi firi; nitori igi kedari ṣubu; nitori ti a ba awọn alagbara jẹ: hu, ẹnyin igi oaku ti Baṣani, nitori a ke igbo ajara lulẹ. 3 Ohùn igbe awọn oluṣọ agutan; nitori ogo…
-
Sakaria 12
Ìlérí Ìdáǹdè fún Jerusalẹmu 1 Ọ̀RỌ-ÌMỌ ọ̀rọ Oluwa fun Israeli, li Oluwa wi, ẹni ti o nnà awọn ọrun, ti o si fi ipilẹ aiye sọlẹ, ti o si mọ ẹmi enia ti mbẹ ni inu rẹ̀. 2 Kiye si i, emi o sọ Jerusalemu di ago iwarìri si gbogbo enia yika, nigbati nwọn o…
-
Sakaria 13
1 LI ọjọ na isun kan yio ṣi silẹ fun ile Dafidi ati fun awọn ara Jerusalemu, fun ẹ̀ṣẹ ati fun ìwa aimọ́. 2 Yio si ṣe li ọjọ na, li Oluwa awọn ọmọ-ogun wi, li emi o ke orukọ awọn òriṣa kuro ni ilẹ na, a kì yio si ranti wọn mọ: ati pẹlu…
-
Sakaria 14
Jerusalẹmu ati Àwọn Orílẹ̀-Èdè 1 KIYESI i, ọjọ Oluwa mbọ̀, a o si pin ikogun rẹ lãrin rẹ. 2 Nitori emi o kó gbogbo orilẹ-ède jọ si Jerusalemu fun ogun; a o si kó ilu na, a o si kó awọn ile, a o si bà awọn obinrin jẹ, abọ̀ ilu na yio lọ si…
-
Haggai 1 yrb
OLUWA pàṣẹ láti tún Tẹmpili Kọ́ 1 LI ọdun keji Dariusi ọba, li oṣù kẹfa, li ọjọ ekini oṣù na, ọ̀rọ Oluwa wá, nipa ọwọ Hagai woli, sọdọ Serubbabeli ọmọ Ṣealtieli, bãlẹ Juda, ati sọdọ Joṣua ọmọ Josedeki, olori alufa, wipe, 2 Bayi li Oluwa awọn ọmọ-ogun wi, Awọn enia wọnyi nsọ pe, Akokò kò…
-
Haggai 2 yrb
Ẹwà Tẹmpili Tuntun náà 1 LI oṣù keje, li ọjọ kọkanlelogun oṣù na, ni ọ̀rọ Oluwa wá nipa ọwọ́ Hagai woli, wipe, 2 Sọ nisisiyi fun Serubbabeli ọmọ Ṣealtieli, bãlẹ Juda, ati fun Joṣua, ọmọ Josedeki, olori alufa, ati fun awọn enia iyokù pe, 3 Tali o kù ninu nyin ti o ti ri ile…
-
Sefania 1
1 Ọ̀RỌ Oluwa ti o tọ̀ Sefaniah wá ọmọ Kuṣi, ọmọ Gedaliah, ọmọ Amariah, ọmọ Hisikiah, li ọjọ Josiah, ọmọ Amoni ọba Juda. Ọjọ́ Ìdájọ́ Ọlọrun 2 Oluwa wipe, emi o mu gbogbo nkan kuro lori ilẹ na patapata. 3 Emi o mu enia ati ẹranko kuro; emi o mu ẹiyẹ oju ọrun kuro, ati…
-
Sefania 2
Ìpè sí Ìrònúpìwàdà 1 Ẹ kó ara nyin jọ pọ̀, ani, ẹ kójọ pọ̀ orilẹ-ède ti kò nani; 2 Ki a to pa aṣẹ na, ki ọjọ na to kọja bi iyàngbò, ki gbigboná ibinu Oluwa to de ba nyin, ki ọjọ ibinu Oluwa ki o to de ba nyin. 3 Ẹ wá Oluwa, gbogbo…
-
Sefania 3
Ẹ̀ṣẹ̀ Jerusalẹmu ati Ìràpadà Rẹ̀ 1 EGBE ni fun ọlọ̀tẹ ati alaimọ́, fun ilu aninilara nì. 2 On kò fetisi ohùn na; on kò gba ẹkọ́; on kò gbẹkẹ̀le Oluwa; on kò sunmọ ọdọ Ọlọrun rẹ̀. 3 Awọn olori rẹ̀ ti o wà lãrin rẹ̀ kiniun ti nke ramùramù ni nwọn; awọn onidajọ rẹ̀ ikõkò…
-
Habakkuku 1
1 Ọ̀rọ-ìmọ ti Habakuku wolii rí. Ìṣubú Ninefe 2 Oluwa, emi o ti ke pẹ to, ti iwọ kì yio fi gbọ́! ti emi o kigbe si ọ, niti ìwa-ipa, ti iwọ kì yio si gbalà! 3 Ẽṣe ti o mu mi ri aiṣedede, ti o si jẹ ki nma wò ìwa-ìka? nitori ikógun ati…
-
Habakkuku 2
Ìdáhùn OLUWA sí Habakuku 1 LORI ibuṣọ́ mi li emi o duro, emi o si gbe ara mi kà ori alore, emi o si ṣọ lati ri ohun ti yio sọ fun mi, ati èsi ti emi o fọ́, nigbati a ba mba mi wi. 2 Oluwa si da mi lohùn, o si wipe, Kọ…
-
Habakkuku 3
Adura Habakuku 1 ADURA Habakuku woli lara Sigionoti. 2 Oluwa, mo ti gbọ́ ohùn rẹ, ẹ̀ru si bà mi: Oluwa, mu iṣẹ rẹ sọji lãrin ọdun, lãrin ọdun sọ wọn di mimọ̀; ni ibinu ranti ãnu. 3 Ọlọrun yio ti Temani wá, ati Ẹni Mimọ́ lati oke Parani. Ogo rẹ̀ bò awọn ọrun, ilẹ aiye…
-
Nahumu 1
1 Ọ̀RỌ-ÌMỌ̀ niti Ninefe. Iwe iran Nahumu ara Elkoṣi. Ibinu OLUWA sí Ìlú Ninefe 2 Ọlọrun njowu, Oluwa si ngbẹsan; Oluwa ngbẹsan, o si kún fun ibinu; Oluwa ngbẹsan li ara awọn ọta rẹ̀, o si fi ibinu de awọn ọta rẹ̀. 3 Oluwa lọra lati binu, o si tobi li agbara, ni didasilẹ̀ kì…
-
Nahumu 2
Ìṣubú Ninefe 1 ATUNIKA de iwaju rẹ (Ninefe): pa ile-iṣọ mọ, ṣọ ọ̀na na, di àmurè ẹ̀gbẹ rẹ ko le, mura girigiri. 2 Nitori Oluwa tun pada si ọlanla Jakobu, gẹgẹ bi ọlanla Israeli: atunidanù ti tú wọn danù, nwọn si ba ẹka àjara wọn jẹ. 3 A sọ asà awọn ọkunrin alagbara rẹ̀ di…
-
Nahumu 3
1 EGBE ni fun ilu ẹjẹ̀ nì! gbogbo rẹ̀ kun fun eké, ati olè, ijẹ kò kuro; 2 Ariwo pàṣan, ati ariwo kikùn kẹkẹ́, ati ti ijọ awọn ẹṣin, ati ti fifò kẹkẹ́. 3 Ẹlẹṣin ti gbe idà rẹ̀ ti nkọ màna, ati ọkọ̀ rẹ̀ ti ndán yànran si oke: ọ̀pọlọpọ si li awọn ẹniti…
-
Mika 1
1 Ọ̀RỌ Oluwa ti o tọ̀ Mika ara Moraṣti wá li ọjọ Jotamu, Ahasi, ati Hesekiah, awọn ọba Juda, ti o ri niti Samaria ati Jerusalemu. Ìpohùnréré Ẹkún nítorí Samaria ati Jerusalẹmu 2 Ẹ gbọ́, gbogbo ẹnyin enia; fetisilẹ, Iwọ ilẹ aiye, ati ẹkún rẹ̀: si jẹ ki Oluwa Ọlọrun ṣe ẹlẹri si nyin, Oluwa…
-
Mika 2
Ìjìyà fún Àwọn Tí Wọn ń Ni Àwọn Talaka Lára 1 EGBE ni fun awọn ti ngbìmọ aiṣedede, ti nṣiṣẹ ibi lori akete wọn! nigbati ojumọ́ mọ́ nwọn nṣe e, nitoripe o wà ni agbara ọwọ́ wọn. 2 Nwọn si nṣe ojukòkoro oko, nwọn si nfi ipá gbà a: ati ile, nwọn a si mu…
-
Mika 3
Mika Bá Àwọn Olórí Israẹli Wí 1 EMI si wipe, Gbọ́, emi bẹ̀ nyin, ẹnyin olori ni Jakobu, ati ẹnyin alakoso ile Israeli; ti nyin kì iṣe lati mọ̀ idajọ bi? 2 Ẹnyin ti o korira ire, ti ẹ si fẹ ibi; ti ẹ já awọ-ara wọn kuro lara wọn, ati ẹran-ara wọn kuro li…
-
Mika 4
Ìjọba Alaafia OLUWA Tí Ó Kárí Ayé 1 YIO si ṣe li ọjọ ikẹhìn, a o fi oke ile Oluwa kalẹ lori awọn oke-nla, a o si gbe e ga jù awọn oke kekeke lọ; awọn enia yio si mã wọ́ sinu rẹ̀. 2 Ọ̀pọlọpọ orilẹ-ède yio si wá, nwọn o si wipe, Ẹ wá,…
-
Mika 5
1 NISISIYI gbá ara rẹ jọ li ọwọ́, Iwọ ọmọbinrin ọwọ́: o ti dó tì wa; nwọn o fi ọ̀pa lu onidajọ Israeli li ẹ̀rẹkẹ. Ọlọrun Ṣèlérí láti Yan Olórí ní Bẹtlẹhẹmu 2 Ati iwọ Betlehemu Efrata; bi iwọ ti jẹ kekere lãrin awọn ẹgbẹgbẹ̀run Juda, ninu rẹ ni ẹniti yio jẹ olori ni Israeli…
-
Mika 6
Ọlọrun bá Israẹli Rojọ́ 1 Ẹ gbọ́ nisisiyi ohun ti Oluwa wi; Dide, ba oke nla wijọ, si jẹ ki oke kékèké gbohùn rẹ. 2 Ẹ gbọ́ ẹjọ Oluwa, ẹnyin oke-nla, ati ẹnyin ipilẹ ilẹ̀ aiye: nitori Oluwa mba awọn enia rẹ̀ wijọ, yio si ba Israeli rojọ. 3 Enia mi, kini mo fi ṣe…
-
Mika 7
Ìwà Ìbàjẹ́ Israẹli 1 EGBE ni fun mi! nitori emi dàbi ikojọpọ̀ eso ẹ̃rùn, bi ẽṣẹ́ ikorè eso àjara: kò si ití kan lati jẹ: akọso ti ọkàn mi fẹ. 2 Oninurere ti run kuro li aiye: kò si si olotitọ kan ninu enia: gbogbo wọn ba fun ẹ̀jẹ, olukuluku wọn nfi àwọn dẹ arakunrin…
-
Jona 1
Jona Ṣe Àìgbọràn sí OLUWA 1 NJẸ ọ̀rọ Oluwa tọ̀ Jona ọmọ Amittai wá, wipe, 2 Dide, lọ si Ninefe, ilu nla nì, ki o si kigbe si i; nitori ìwa buburu wọn goke wá iwaju mi. 3 Ṣugbọn Jona dide lati sá lọ si Tarṣiṣi kuro niwaju Oluwa, o si sọkalẹ lọ si Joppa;…
-
Jona 2
Adura Jona 1 NIGBANA ni Jona gbadura si Oluwa Ọlọrun rẹ̀ lati inu ẹja na wá, 2 O si wipe, Emi kigbe nitori ipọnju mi si Oluwa, on si gbohùn mi; mo kigbe lati inu ipo-okú, iwọ si ti gbohùn mi. 3 Nitoriti iwọ ti sọ mi sinu ibu, larin okun; iṣàn omi si yi…
-
Jona 3
Jona Gbọ́ràn sí OLUWA Lẹ́nu 1 Ọ̀RỌ Oluwa si tọ̀ Jona wá lẹ̃keji, wipe, 2 Dide, lọ si Ninefe, ilu nla nì, ki o si kede si i, ikede ti mo sọ fun ọ. 3 Jona si dide, o si lọ si Ninefe, gẹgẹ bi ọ̀rọ Oluwa. Ninefe si jẹ ilu nla gidigidi tó irin…
-
Jona 4
Ibinu Jona ati Àánú Ọlọrun 1 ṢUGBỌN o bà Jona ninu jẹ́ gidigidi, o si binu pupọ̀. 2 O si gbadura si Oluwa, o si wipe, Emi bẹ ọ, Oluwa, ọ̀rọ mi kọ yi nigbati mo wà ni ilẹ mi? nitorina ni mo ṣe salọ si Tarṣiṣi ni iṣaju: nitori emi mọ̀ pe, Ọlọrun olore-ọfẹ…
-
Obadiah 1 yrb
1 IRAN ti Obadiah. Bayi ni Oluwa Ọlọrun wi niti Edomu; Awa ti gbọ́ ihìn kan lati ọdọ Oluwa wá, a si ti rán ikọ̀ kan si ãrin awọn keferi, Ẹ dide, ẹ si jẹ ki a dide ogun si i. OLUWA Yóo Jẹ Edomu Níyà 2 Kiyesi i, mo ti sọ iwọ di kekere…
-
Amosi 1
1 Ọ̀RỌ Amosi, ẹniti o wà ninu awọn darandaran Tekoa, ti o ri niti Israeli li ọjọ ọba Ussiah ọba Juda, ati li ọjọ Jeroboamu ọmọ Joaṣi ọba Israeli, ọdun meji ṣãju isẹ̀lẹ nì. 2 O si wipe, Oluwa yio bu jade lati Sioni wá, yio si fọ̀ ohùn rẹ̀ lati Jerusalemu wá; ibùgbe awọn…
-
Amosi 2
Moabu 1 BAYI li Oluwa wi; nitori irekọja mẹta ti Moabu, ati nitori mẹrin, emi kì o yi iyà rẹ̀ kuro; nitori o ti sun egungun ọba Edomu di ẽrú. 2 Ṣugbọn emi o rán iná kan sara Moabu, yio si jó ãfin Kirioti wọnni run: Moabu yio si kú pẹlu ariwo, pẹlu iho ayọ̀,…
-
Amosi 3
1 Ẹ gbọ̀ ọ̀rọ yi ti Oluwa ti sọ si nyin, ẹnyin ọmọ Israeli, si gbogbo idile ti mo mú goke lati ilẹ Egipti wá, wipe, 2 Ẹnyin nikan ni mo mọ̀ ninu gbogbo idile aiye: nitorina emi o bẹ̀ nyin wò nitori gbogbo ẹ̀ṣẹ nyin. Iṣẹ́ Wolii 3 Ẹni meji lè rìn pọ̀, bikòṣepe…
-
Amosi 4
1 Ẹ gbọ́ ọ̀rọ yi, ẹnyin ọmọ malu Baṣan, ti o wà li oke nla Samaria, ti o nni talakà lara, ti o ntẹ̀ alaini rẹ́, ti o nwi fun oluwa wọn pe, Gbe wá, ki a si mu. 2 Oluwa Ọlọrun ti bura ninu iwà-mimọ́ rẹ̀, pe, Sa wò o, ọjọ wọnni yio de…
-
Amosi 5
Ìpè sí Ìrònúpìwàdà 1 Ẹ gbọ́ ọ̀rọ yi ti emi gbe soke si nyin, ani ohùnrére ẹkun, ẹnyin ile Israeli. 2 Wundia Israeli ti ṣubu; kì yio dide mọ: a kọ̀ ọ silẹ lori ilẹ rẹ̀; kò si ẹniti yio gbe e dide. 3 Nitori bayi li Oluwa Ọlọrun wi; Ilu ti o jade lọ…
-
Amosi 6
Ìparun Israẹli 1 EGBE ni fun ẹniti ara rọ̀ ni Sioni, ati awọn ti o gbẹkẹ̀le oke nla Samaria, awọn ti a pè ni ikini ninu awọn orilẹ-ède, awọn ti ile Israeli tọ̀ wá! 2 Ẹ kọja si Kalne, si wò; ẹ si ti ibẹ̀ lọ si Hamati nla: lẹhìn na ẹ sọ̀kalẹ lọ si…
-
Amosi 7
Ìran Nípa Eeṣú 1 BAYI li Oluwa Ọlọrun ti fi hàn mi; si wò o, o dá ẽṣú ni ibẹ̀rẹ irú-soke idàgba ikẹhin, si wò o, idàgba ikẹhìn lẹhìn ike-kuro ti ọba nì. 2 O si ṣe, ti nwọn jẹ koriko ilẹ na tan, nigbana ni mo wipe, Oluwa Ọlọrun, darijì, emi bẹ̀ ọ: Jakobu…
-
Amosi 8
Ìran Nípa Agbọ̀n Èso 1 BAYI li Oluwa Ọlọrun ti fi hàn mi: si kiyesi i, agbọ̀n eso ẹrùn kan. 2 On si wipe, Amosi, kili ohun ti iwọ ri? Emi si wipe, Agbọ̀n eso ẹrùn ni. Nigbana li Oluwa wi fun mi pe, Opin de si Israeli enia mi; emi kì yio tún kọja…
-
Amosi 9
Amo, 9 Ìdájọ́ OLUWA 1 MO ri Oluwa o duro lori pẹpẹ: o si wipe, Lù itẹrigbà ilẹ̀kun, ki awọn òpo ki o le mì: si ṣá wọn li ori, gbogbo wọn; emi o si fi idà pa ẹni ikẹhìn wọn: ẹniti o sá ninu wọn, kì yio salọ gbe; ati ẹniti o sa asalà…
-
Joeli 1
1 Ọ̀RỌ Oluwa ti o tọ̀ Joeli ọmọ Petueli wá. Ìdárò Nítorí Ìparun Nǹkan Ọ̀gbìn 2 Gbọ́ eyi, ẹnyin arugbo, si fi eti silẹ, gbogbo ẹnyin ará ilẹ na. Eyi ha wà li ọjọ nyin, tabi li ọjọ awọn baba nyin? 3 Ẹ sọ ọ fun awọn ọmọ nyin, ati awọn ọmọ nyin fun awọn…
-
Joeli 2
Ọ̀wọ́ Eeṣú, gẹ́gẹ́ bí Àmì Ìkéde Ọjọ́ OLUWA 1 Ẹ fun ipè ni Sioni, ẹ si dá idagìri ni oke mimọ́ mi; jẹ ki awọn ará ilẹ na warìri: nitoriti ọjọ Oluwa mbọ̀ wá, nitori o kù si dẹ̀dẹ; 2 Ọjọ òkunkun ati òkudu, ọjọ ikũku ati òkunkun biribiri, bi ọyẹ̀ owurọ̀ ti ilà bò…
-
Joeli 3
OLUWA Yóo Ṣe Ìdájọ́ Àwọn Orílẹ̀-Èdè 1 NITORINA kiyesi i, li ọjọ wọnni, ati li akokò na, nigbati emi o tun mu igbèkun Juda ati Jerusalemu padà bọ̀. 2 Emi o kó gbogbo orilẹ-ède jọ pẹlu, emi o si mu wọn wá si afonifojì Jehoṣafati, emi o si ba wọn wijọ nibẹ̀ nitori awọn enia…
-
Hosea 1 yrb
1 Ọ̀RỌ Oluwa ti o tọ̀ Hosea, ọmọ Beeri wá, li ọjọ Ussiah, Jotamu, Ahasi, ati Hesekiah, awọn ọba Juda, ati li ọjọ Jeroboamu ọmọ Joaṣi, ọba Israeli. Iyawo Hosiaati Àwọn Ọmọ Rẹ̀ 2 Ibẹ̀rẹ ọ̀rọ Oluwa si Hosea. Oluwa si wi fun Hosea, pe, Lọ, fẹ́ agbère obinrin kan fun ara rẹ, ati awọn…
-
Hosea 2 yrb
1 Ẹ wi fun awọn arakunrin nyin, Ammi; ati fun awọn arabinrin nyin, Ruhama. Gomeri Alaiṣootọ–Israẹli Alaiṣootọ 2 Ẹ ba iya nyin wijọ, ẹ wijọ; nitori on kì iṣe aya mi, bẹ̃ni emi kì iṣe ọkọ rẹ̀: nitori na jẹ ki on ki o mu gbogbo agberè rẹ̀ kuro ni iwaju rẹ̀, ati gbogbo panṣaga…
-
Hosea 3 yrb
Hosea ati Obinrin Alaiṣootọ 1 OLUWA sí wi fun mi pe, Tun lọ, fẹ́ obinrin kan ti iṣe olùfẹ́ ọrẹ rẹ̀, ati panṣagà, gẹgẹ bi ifẹ Oluwa si awọn ọmọ Israeli, ti nwò awọn ọlọrun miràn, ti nwọn si nfẹ́ akàra eso àjara. 2 Bẹ̃ni mo rà a fun ara mi ni fadakà mẹ̃dogun, ati…
-
Hosea 4 yrb
OLUWA Fi Ẹ̀sùn Kan Israẹli 1Ẹ gbọ́ ọ̀rọ Oluwa, ẹnyin ọmọ Israeli; nitori Oluwa ni ẹjọ kan ba awọn ara ilẹ na wi, nitoriti kò si otitọ, tabi ãnu, tabi ìmọ Ọlọrun ni ilẹ na. 2Nipa ibura, ati eke, ati ipani, ati olè, ati iṣe panṣaga, nwọn gbìjà, ẹ̀jẹ si nkàn ẹ̀jẹ. 3Nitorina ni ilẹ…
-
Hosea 5 yrb
1 Ẹ gbọ́ eyi, ẹnyin alufa: si tẹtilelẹ ẹnyin ile Israeli; ki ẹ si gbọ́, ile ọba na; nitori idajọ kàn nyin, nitoriti ẹnyin ti jẹ ẹgẹ́ si Mispa, àwọn ti a nà silẹ lori Tabori. 2 Awọn ọlọ̀tẹ si jinlẹ ni pipanirun, emi o jẹ olùbawi gbogbo wọn. 3 Emi mọ̀ Efraimu, Israeli kò…
-
Hosea 6 yrb
Àwọn Eniyan náà Ṣe Ìrònúpìwàdà Èké 1 Ẹ wá, ẹ jẹ ki a yipadà si Oluwa: nitori o ti fà wa ya, on o si mu wa lara da; o ti lù wa, yio si tun wa dì. 2 Lẹhìn ijọ meji, yio tún wa jí: ni ijọ kẹta yio ji wa dide, awa o…
-
Hosea 7 yrb
1 NIGBATI emi iba mu Israeli li ara dá, nigbana ni ẹ̀ṣẹ Efraimu fi ara hàn, ati ìwa-buburu Samaria; nitori nwọn ṣeké; olè si wọle, ọwọ́ olè si nkoni lode. 2 Nwọn kò si rò li ọkàn wọn pe, emi ranti gbogbo ìwa-buburu wọn: nisisiyi iṣẹ ara wọn duro yi wọn ka; nwọn wà niwaju…
-
Hosea 8 yrb
OLUWA Bá Israẹli Wí nítorí Ìwà Ìbọ̀rìṣà 1 FI ipè si ẹnu rẹ. Yio wá bi idì si ile Oluwa, nitori nwọn ti re majẹmu mi kọja, nwọn si ti rú ofin mi. 2 Nwọn o kigbe si mi pe, Ọlọrun mi, awa Israeli mọ̀ ọ. 3 Israeli ti gbe ohunrere sọnù; ọta yio lepa…
-
Hosea 9 yrb
Hosea Kéde Ìjìyà fún Israẹli 1 MÁṢE yọ̀, Israeli, fun ayọ̀, bi awọn enia miràn: nitori iwọ ti ṣe agbère lọ kuro lọdọ Ọlọrun rẹ, iwọ ti fẹ́ èrè lori ilẹ ipakà gbogbo. 2 Ilẹ ipakà ati ohun ifunti kì yio bọ́ wọn, ọti-waini titun yio si tan ninu rẹ̀. 3 Nwọn kì yio gbe…
-
Hosea 10 yrb
1 ÁJARA ofo ni Israeli, o nso eso fun ara rẹ̀; gẹgẹ bi ọ̀pọ eso rẹ̀ li o mu pẹpẹ pọ̀ si i; gẹgẹ bi didara ilẹ rẹ̀ ni nwọn yá ere daradara. 2 Ọkàn wọn dá meji; nisisiyi ni nwọn o jẹbi; on o wó pẹpẹ wọn lulẹ, on o si ba ere wọn…
-
Hosea 11 yrb
Ìfẹ́ Ọlọrun sí Àwọn Eniyan Rẹ̀, Ọlọ̀tẹ̀ 1 NIGBATI Israeli wà li ọmọde, nigbana ni mo fẹ́ ẹ, mo si pè ọmọ mi lati Egipti jade wá. 2 Bi nwọn ti pè wọn, bẹ̃ni nwọn lọ kuro lọdọ wọn: nwọn rubọ si Baalimu, nwọn si fi turari joná si ere fifin. 3 Mo kọ́ Efraimu…
-
Hosea 12 yrb
1 EFRAIMU njẹ afẹfẹ́, o si ntọ̀ afẹfẹ́ ila-õrun lẹhìn: o nmu eke ati iparun pọ̀ si i lojojumọ; nwọn si ba awọn ara Assiria da majẹmu, nwọn si nrù ororo lọ si Egipti. 2 Oluwa ni ẹjọ kan ba Juda rò pẹlu, yio si jẹ Jakobu ni iyà gẹgẹ bi ọ̀na rẹ̀; gẹgẹ bi…
-
Hosea 13 yrb
Paríparí Ìdájọ́ Israẹli 1 NIGBATI Efraimu sọ̀rọ, ìwarìri ni; o gbe ara rẹ̀ ga ni Israeli; ṣugbọn nigbati o ṣẹ̀ ninu Baali, o kú. 2 Nisisiyi, nwọn si dá ẹ̀ṣẹ kún ẹ̀ṣẹ, nwọn si ti fi fàdakà wọn ṣe ere didà fun ara wọn, ati òriṣa ìmọ wọn: iṣẹ oniṣọnà ni gbogbo rẹ̀; nwọn wi…
-
Hosea 14 yrb
Ẹ̀bẹ̀ Hosea fún Israẹli 1 ISRAELI, yipadà si Oluwa Ọlọrun rẹ, nitori iwọ ti ṣubu ninu aiṣedẽde rẹ. 2 Mu ọ̀rọ pẹlu nyin, ẹ si yipadà si Oluwa: ẹ wi fun u pe, Mu aiṣedẽde gbogbo kuro, si fi ore-ọfẹ gbà wa: bẹ̃ni awa o fi ọmọ malu ète wa san a fun ọ. 3…
-
Danieli 1
Dan, 1 Àwọn Ọdọmọkunrin kan ní Ààfin Nebukadnessari 1 LI ọdun kẹta ijọba Jehoiakimu, ọba Juda ni Nebukadnessari, ọba Babeli, wá si Jerusalemu, o si do tì i. 2 Oluwa si fi Jehoiakimu, ọba Juda le e lọwọ, pẹlu apakan ohun-elo ile Ọlọrun, ti o kó lọ si ilẹ Ṣinari, si ile oriṣa rẹ̀: o…
-
Danieli 2
åDan, 2 Àlá Nebukadnessari 1 ATI li ọdun keji ijọba Nebukadnessari, Nebukadnessari lá alá nipa eyi ti ọkàn rẹ̀ kò fi le ilẹ ninu rẹ̀, ti orun si dá loju rẹ̀. 2 Nigbana ni ọba paṣẹ pe, ki a pè awọn amoye ati ọlọgbọ́n, ati awọn oṣó, ati awọn Kaldea wá, lati fi alá ọba…
-
Danieli 3
Dan, 3 Nebukadinessari Pàṣẹ pé kí Gbogbo Eniyan máa Sin Ère Wúrà tí ó gbé kalẹ̀ 1 NEBUKADNESSARI ọba, si yá ere wura kan, eyi ti giga rẹ̀ jẹ ọgọta igbọnwọ, ati ibú rẹ̀ jẹ igbọnwọ mẹfa: o si gbé e kalẹ ni pẹtẹlẹ Dura, ni igberiko Babeli. 2 Nigbana ni Nebukadnessari ọba, ranṣẹ lọ…
-
Danieli 4
Dan, 4 Àlá Keji tí Nebukadinesari Lá 1 NEBUKADNESSARI ọba, si gbogbo enia, orilẹ, ati ède, ti o ngbe gbogbo agbaiye; ki alafia ki o ma pọ̀ si i fun nyin. 2 O tọ loju mi lati fi àmi ati iṣẹ iyanu ti Ọlọrun, Ọga-ogo, ti ṣe si mi hàn. 3 Ami rẹ̀ ti tobi…
-
Danieli 5
Dan, 5 Àsè Belṣsasari 1 BELṢASSARI, ọba se àse nla fun ẹgbẹrun awọn ijoye rẹ̀, o si nmu ọti-waini niwaju awọn ẹgbẹrun na. 2 Bi Belṣassari ti tọ́ ọti-waini na wò, o paṣẹ pe ki nwọn ki o mu ohun-elo wura, ati ti fadaka wá, eyiti Nebukadnessari baba rẹ̀, kó jade lati inu tempili ti…
-
Danieli 6
Dan, 6 Daniẹli ninu Ihò Kinniun 1 O ṣe didùn inu Dariusi lati fi ọgọfa arẹ bãlẹ sori ijọba na, ti yio wà lori gbogbo ijọba; 2 Ati lori awọn wọnyi ni alakoso mẹta: Danieli si jẹ ọkan ninu wọn: ki awọn arẹ bãlẹ ki o le ma jiyin fun wọn, ki ọba ki o…
-
Danieli 6
Dan, 6 Daniẹli ninu Ihò Kinniun 1 O ṣe didùn inu Dariusi lati fi ọgọfa arẹ bãlẹ sori ijọba na, ti yio wà lori gbogbo ijọba; 2 Ati lori awọn wọnyi ni alakoso mẹta: Danieli si jẹ ọkan ninu wọn: ki awọn arẹ bãlẹ ki o le ma jiyin fun wọn, ki ọba ki o…
-
Danieli 7
Dan, 7 Àlá Daniẹli Nípa Àwọn Ẹranko Mẹrin 1 LI ọdun kini Belṣassari, ọba Babeli, ni Danieli lá alá, ati iran ori rẹ̀ lori akete rẹ̀: nigbana ni o kọwe alá na, o si sọ gbogbo ọ̀rọ na. 2 Danieli dahùn, o si wipe, Mo ri ni iran mi li oru, si kiyesi i, afẹfẹ…
-
Danieli 8
Dan, 8 Ìran tí Daniẹli Rí Nípa Àgbò ati Ewúrẹ́ 1 LI ọdun kẹta ijọba Belṣassari ọba, iran kan fi ara hàn fun mi, ani emi Danieli, lẹhin iran ti emi ri ni iṣaju. 2 Emi si ri loju iran, o si ṣe nigbati mo ri, ti mo si wà ni Ṣuṣani, li ãfin, ti…
-
Danieli 9
Dan, 9 Daniẹli Gbadura fún Àwọn Eniyan Rẹ̀ 1 LI ọdun kini Dariusi, ọmọ Ahasuerusi, lati iru-ọmọ awọn ara Media wá, ti a fi jọba lori ilẹ-ọba awọn ara Kaldea; 2 Li ọdun kini ijọba rẹ̀ li emi Danieli fiyesi lati inu iwe, iye ọdun, nipa eyi ti ọ̀rọ Oluwa tọ Jeremiah, woli wá, pe…